Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 12 Oṣù Kínní
Ìrísí

- 1964 – Àwọn aṣágun ní Zanzibar (àsìá), bẹ̀rẹ̀ ìṣọ̀tẹ̀ tó únjẹ́ Ìjídìde Zanzibar, wọ́n sì kéde orílẹ̀òmìnira.
- 2010 – Ìwàrìrì-ilẹ̀ ní Haiti tó ṣelẹ̀ pa àwọn ènìyàn 230,000, ó sì pa ọ̀pọ̀ olúìlú Port-au-Prince run.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1940 – Rasaki Akanni Okoya, onísòwò ará Nàìjíríà
- 1944 – Joe Frazier, ajaese ará Amẹ́ríkà (al. 2011)
- 1948 – Khalid Abdul Muhammad, alakitiyan ará Amẹ́ríkà (al. 2001)
- 1952 – Walter Mosley, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà.
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1965 – Lorraine Hansberry, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (ib. 1930),
- 1983 – Rebop Kwaku Baah, onílù ará Ghánà (ib. 1944).
- 1997 – Charles B. Huggins, ẹlẹ́bùn Nobel nínú Ìwòsàn ará Kánádà (ib. 1901).
![]() | Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |