Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 13 Oṣù Kẹrin
Ìrísí
- 1849 – Hungary di orílẹ̀-èdè olómìnira.
- 1963 – Níbi Ẹ̀bùn Akadẹ́mì, Sidney Poitier di ọmọkùnrin Áfríkà Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ tó gba ẹ̀bùn Òṣeré Ọkùnrin Dídárajùlọ fún fílmù Lilies of the Field.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1743 – Thomas Jefferson, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà kẹta (al. 1826)
- 1906 – Samuel Beckett, olùkọ̀wé ọmọ Írẹ́lándì (al. 1989)
- 1922 – Julius Nyerere (fọ́tò), Ààrẹ orílẹ̀-èdè Tansania (al. 1999)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1868 – Tewodros II, Ọba ilẹ̀ Ethiopia (ib. 1818)
- 1966 – Abdul Salam Arif, olóṣèlú ará Irak (ib. 1921)
- 2005 – Johnnie Johnson, olórin blues ará Amẹ́ríkà (b. 1924)