Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 14 Oṣù Keje
Appearance
- 1789 – Ìjídìde Fránsì: àwọn aráàlú Paris dìgbò lu Bastille.
- 1943 – Ní Joplin, Missouri, Ìbòji Ìrántí Omọorílẹ̀-èdè George Washington Carver di Ìbòji Ìrántí Omọorílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ tó ṣe ẹ̀yẹ ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1816 – Arthur de Gobineau, amòye ará Fránsì (al. 1882)
- 1913 – Gerald Ford, Ààrẹ 38k Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (al. 2006)
- 1960 – Angélique Kidjo, akọrin ará Benin
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1816 – Francisco de Miranda, olùjídìde ará Venezuela (ib. 1750)
- 1954 – Jacinto Benavente, olùkọ̀wé ará Spẹ́ìn (ib. 1866)