Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 18 Oṣù Kejìlá
Ìrísí
![Steve Biko](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/yo/thumb/a/a4/Steve_Biko.jpg/100px-Steve_Biko.jpg)
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1917 – Ossie Davis, osere ati alaktiyan ara Amerika (al. 2005)
- 1924 – Cicely Tyson, osere ara Amerika
- 1946 – Steve Biko (foto), alakitiyan ara Guusu Afrika (al. 1977)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1973 – Allama Rasheed Turabi, amoye ara Pakistani (ib. 1908)
- 2011 – Václav Havel, amoye, oloselu ati aare ile Tseki Olominira (ib. 1936)
- 2012 – Mustafa Ould Salek, oloselu ara Mauritania, Aare ile Mauritania (ib. 1936)