Václav Havel
Václav Havel | |
---|---|
![]() | |
1st President of the Czech Republic | |
In office 2 February 1993 – 2 February 2003 | |
Alákóso Àgbà |
Václav Klaus Josef Tošovský Miloš Zeman Vladimír Špidla |
Asíwájú | Position established |
Arọ́pò | Václav Klaus |
10th President of Czechoslovakia | |
Lórí àga 29 December 1989 – 20 July 1992 | |
Alákóso Àgbà |
Marián Čalfa Jan Stráský |
Asíwájú | Gustáv Husák |
Arọ́pò | Position abolished |
Personal details | |
Ọjọ́ìbí |
Prague, Czechoslovakia (now Czech Republic) | 5 Oṣù Kẹ̀wá 1936
Aláìsí |
18 December 2011 Hrádeček, Czech Republic | (ọmọ ọdún 75)
Ẹgbẹ́ olóṣèlu |
Independent Civic Forum (1989–1993) |
Spouse(s) |
Olga Šplíchalová (1964–1996) Dagmar Veškrnová (1997–2011; his death) |
Alma mater |
Czech Technical University in Prague Faculty of Theatre |
Profession | Playwright |
Signature |
![]() |
Website |
www.vaclavhavel.cz www.vaclavhavel-library.org |
Václav Havel (Àdàkọ:IPA-cs) (5 October 1936 – 18 December 2011) je Tseki olukereitage, alaroko, alakitiyan ati oloselu. Ohun ni eni ikewa ati to gbeyin bi Aare ile Czechoslovakia (1989–92) ati eni akoko bi Aare ile Tseki Olominira (1993–2003). O ti ko ere itage to ju ogun lo ati awon iwe miran ti won ti je yiyiledepada kakiriaye. O gba Eso Aare fun Ominira ti Amerika, Eso Ominira Filadelfia, Enioto ile Kanada, ati Olusoju Ebun Eriokan. Bakanna ni 2005 o je didiboyan bi eni omowe 4th nini ibo gbogbo aye ti iwe olosoosu Prospect Magazine se larin awon omowe 100 olokiki julo.[1]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "Prospect Intellectuals: The 2005 List". Retrieved 6 April 2010.
|