Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 1 Oṣù Keje
Ìrísí
Ọjọ́ 1 Oṣù Keje: Ọjọ́ Ìlómìnira ní Somalia (1960), Burundi àti Rwanda (1962)
- 1837 – Sístẹ́mù ìforúkọsílẹ̀ aráàlú fún àwọn ìbímọ, ìgbéyàwọ́ àti ikú jẹ́ dídásílẹ̀ ní Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì àti Wales.
- 1921 – Ẹgbẹ́ Kọ́múnístì ilẹ̀ Ṣáínà jẹ́ dídásílẹ̀.
- 1960 – Ghánà di Orílẹ̀-èdè olómìnira àti Kwame Nkrumah gẹ́gẹ́bí Ààrẹ àkọ́kọ́ rẹ̀.
- 1979 – Sony ṣe ìkéde Walkman (foto).
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1646 – Gottfried Leibniz, German mathematician (d. 1716)
- 1921 – Seretse Khama, Botswanan politician (d. 1980)
- 1961 – Carl Lewis, American athlete
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1971 – William Lawrence Bragg, English physicist, Nobel laureate (b. 1890)
- 1974 – Juan Perón, 29th and 41st President of Argentina (b. 1895)
- 2005 – Luther Vandross, American singer (b. 1951)