Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 21 Oṣù Kàrún
Appearance
- 1851 – Oko ẹrú jẹ́ fífòfindè ní Kòlómbìà.
- 1904 – Fédération Internationale de Football Association (FIFA) jẹ́ dídásílẹ̀ ní Paris.
- 1991 – Mengistu Haile Mariam (fọ́tò), ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú Ará ilẹ̀ Ethiópíà, sá kúrò ní Ethiopia, èyí mú òpin wá sí Ogun Abẹ́lé Ethiopia.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1688 – Alexander Pope, akọewì ọmọ Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1744)
- 1941 – Ronald Isley, àkọrin ará Amẹ́ríkà (The Isley Brothers)
- 1972 – The Notorious B.I.G., rapper ará Amẹ́ríkà (al. 1997)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1670 – Niccolo Zucchi, atòràwọ̀ ará Itálíà (ib. 1586)
- 1964 – James Franck, ẹlẹ́bùn Nobel ará Jẹ́mánì (ib. 1882)
- 1991 – Rajiv Gandhi, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Índíà (ib. 1944)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |