Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 24 Oṣù Kẹ̀wá
Ìrísí
Ọjọ́ 24 Oṣù Kẹ̀wá: Ọjọ́ òmìnira ni Zambia (1964)
- 1998 – Ìgbéra ìrán-loṣe Deep Space 1
- 2003 – Bàálù Concorde (fótò) ṣiṣẹ́ fún ìgbà ìgbèyìn.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1932 – Pierre-Gilles de Gennes, onímọ̀ físíksì ará Fránsì (al. 2007)
- 1932 – Robert Mundell, onímọ̀ òkòwò ará Kánádà
- 1948 – Kweisi Mfume, olóṣèlú àti alákitiyan ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1601 – Tycho Brahe, onímọ̀ ìrawọ̀ ará Dẹ́nmákì (ib. 1546)
- 1972 – Jackie Robinson, agbá baseball ará Amẹ́ríkà (ib. 1919)
- 2005 – Rosa Parks, alákitiyan ará Amẹ́ríkà (ib. 1913)