Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 25 Oṣù Kẹ̀wá
Appearance
- 1962 – Uganda darapọ̀ mọ́ Ajọ àwọn Orílẹ̀-èdè.
- 1962 – Awọn òyìnbó sọ Nelson Mandela sí ẹ̀wọ̀n fún ọdún máàrún.
- 1997 – Denis Sassou-Nguesso di Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò lẹ́yìn tí Ogun Abẹ́lé ti lé Ààrẹ Pascal Lissouba kúrò ní ipò ní Brazzaville.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1881 – Pablo Picasso, oníṣọ̀nà ará Spéínì (al. 1973)
- 1900 – Funmilayo Ransome-Kuti, alákitiyan ará Nàìjíríà (al. 1978)
- 1975 – Zadie Smith, olùkọ̀wé ará Bírítánì
Àwọn aláìsí lóòní...
- 2010 – Gregory Isaacs, akọrin ará Jamáíkà (ib. 1951)