Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 26 Oṣù Kẹ̀wá
Ìrísí
Ọjọ́ 26 Oṣù Kẹ̀wá: Ọjọ́ Ọmọ Orílẹ̀-èdè ní Austria.
- 1994 - Ísráẹ́lì àti Jordan fẹnukò lórí àdèhùn àlàfíà.
- 2000 – Laurent Gbagbo takes over as president of Côte d'Ivoire following a popular uprising against President Robert Guéï.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1911 - Mahalia Jackson, akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 1972)
- 1916 - François Mitterrand - Ààrẹ ilẹ̀ Fransi (al. 1996)
- 1947 - Hillary Rodham Clinton, olóṣèlú àti Alákóso Òrọ̀ Okèrè Amẹ́ríkà 67k
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1909 – Itō Hirobumi, Alakoso Agba Japan (ib. 1841)
- 1952 – Hattie McDaniel, akọrin àti òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1895)
- 1979 – Park Chung-hee, Ààrẹ Kòrẹ́à Gúúsù (ib. 1917)