Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 25 Oṣù Kejìlá
Ìrísí
Ọjọ́ 25 Oṣù Kejìlá: Kérésìmesì (Gregorian Calendar)
- 320 – Ijo Katholiki sedasile ojo yi bi ojoibi Jesu Kristi (aworan).
- 2009 – Umar Farouk Abdulmutallab unsuccessfully attempts a terrorist attack against the US while on board a flight to Detroit Metro Airport Northwest Airlines Flight 253.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1642 – Isaac Newton, asesayensi ara Ilegeesi (al. 1727)
- 1918 – Anwar Sadat, Aare ile Egypti (al. 1981)
- 1970 – Emmanuel Amuneke, agbaboolu-elese ara Naijiria
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1977 – Charles Chaplin, osere filmu ara Britani (ib. 1889).
- 1995 – Emmanuel Levinas, amoye ara Fransi (ib. 1906)
- 2006 – James Brown (foto), akorin ara Amerika (ib. 1933)