Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 26 Oṣù Kejìlá
Appearance
Ọjọ́ 26 Oṣù Kejìlá: Ọjọ́ Ìsimi Boxing; Odun Kwanzaa bẹ̀rẹ̀
- 1792 – Ìdájọ́ ìdópin Louis 16k ilẹ̀ Fránsì bẹ̀rẹ̀ ní Paris.
- 1908 – Boxer Jack Johnson became the first African American Heavyweight Champion of the World after defeating Canadian Tommy Burns in Sydney.
- 2006 – paipu epo petrolu be ni ilu Eko, Naijiria, o pa 260 eniyan.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1791 – Charles Babbage, English mathematician and inventor (al. 1871)
- 1893 – Mao Zedong (fọ́tò), olori orile-ede Saina (al. 1976).
- 1930 – Adebáyò Faleti, osere ati oludari ara Naijiria
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1972 – Harry Truman, Aare 33k orile-ede Amerika (ib. 1884).
- 1985 – Jackie Ormes, ayàwòrẹ́ẹ̀rín ará Amẹ́ríkà (ib. 1911)
- 1997 – Cornelius Castoriadis, Greek philosopher and economist (b. 1922)