Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 28 Oṣù Kejìlá
Ìrísí
- 1836 – Spéìn faramọ́ ìlómìnira Mẹ́ksíkò.
- 2008 – Ogun ní Sòmálíà: Àwọn ológun láti Somalia àti Ethiopia gbẹ́sẹ̀ lé Mogadishu láilátakò.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1856 – Woodrow Wilson, Ààrẹ 28k Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (al. 1924)
- 1924 – Milton Obote, Ààrẹ Ùgándà 2k (al. 2005)
- 1954 – Denzel Washington, òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1663 – Francesco Maria Grimaldi, aṣesáyẹ́nsì ọmọ Itálíà (ib. 1618)
- 1976 – Freddie King, olórin ará Amẹ́ríkà (ib. 1934)
- 2018 – Shehu Shagari, ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà (ib. 1925)