Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 27 Oṣù Kejìlá
Ìrísí
- 1831 - Charles Darwin wo oko ojuomi HMS Beagle.
- 1945 - Idasile Àjọ Elétòowó Àkáríayé
- 1979 – Isokan Sofieti gbogun ti Afghanistan
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1571 - Johannes Kepler, onimo mathimatiki ara Jemani (al. 1630).
- 1654 – Jacob Bernoulli, onimo mathimatiki ara Switsalandi (al. 1705)
- 1822 - Louis Pasteur, asiseoloogun ara Fransi (al. 1895).
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1972 – Lester B. Pearson, 14th Prime Minister of Canada (ib. 1897)
- 1978 – Houari Boumediène, President of Algeria (ib. 1932)
- 2007 - Benazir Bhutto, oloselu ara Pakistan (ib. 1953).