Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 5 Oṣù Kínní
Ìrísí
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1928 – Walter Mondale, olóṣẹ̀lú ará Amẹ́ríkà
- 1932 – Umberto Eco, olùkọ̀wé ará Itálíà
- 1938 – Ngũgĩ wa Thiong'o, olùkọ̀wé ará Kẹ́nyà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1933 – Calvin Coolidge, Ààrẹ 30k Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (ib. 1872)
- 1943 – George Washington Carver, olùkọ́ni ará Amẹ́ríkà (ib. 1864)
- 1970 – Max Born, aṣefísíksì ọmọ jẹ́máni Brítánì (ib. 1882).