Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 7 Oṣù Kejì
Ìrísí
Ọjọ́ 7 Oṣù Kejì: Ọjọ́ Ìlómìnira ní Grenada (1974)
- 1962 – Orílẹ̀-èdè Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà fòfinde gbogbo ọjà sí àti láti Kúbà.
- 1979 – Pluto bọ́ sínú ọ̀nàìyípò Neptune fún ìgbà àkọ́kọ́ látìgbà tí àwọn méjèjì jẹ́ wíwárí.
- 1986 – Ìjọba ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n Ààrẹ Jean-Claude Duvalier wásópin ní Haiti, nígbà tó sákúrò níbẹ̀.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1812 – Charles Dickens, olùkọ̀wé ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1870)
- 1885 – Sinclair Lewis, ẹlẹ́bùn Nobel ará Amẹ́ríkà (al. 1951)
- 1965 – Chris Rock (fọ́tò), aláwàdà àti òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1937 – Elihu Root, ẹlẹ́bùn Nobel ará Amẹ́ríkà (ib. 1845)
- 1964 – Sophoklis Venizelos, olóṣẹ̀lú ọmọ Grííkì (ib. 1894)
- 1986 – Cheikh Anta Diop, akọìtàn ará Senegal (ib. 1923)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |