Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 8 Oṣù Kejì
Appearance
- 1974 – Ìfipágbàjọba ológun ní Upper Volta.
- 1979 – Denis Sassou-Nguesso di Ààrẹ Orílẹ̀olómìnira ilẹ̀ Kóngò fún ìgbà àkọ́kọ́.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1612 – Samuel Butler, akọewì ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1680)
- 1700 – Daniel Bernoulli, onímathimátíkì ọmọ Hólàndì (al. 1782)
- 1834 – Dmitri Mendeleev (fọ́tò), aṣekẹ́místrì ará Rọ́síà (al. 1907)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1921 – Peter Kropotkin, amòye ará Rọ́síà (ib. 1842)
- 1999 – Iris Murdoch, olùkòwé ará Írẹ́lándì (ib. 1919)
- 1957 – John von Neumann, aṣefísíksì àti onímathimátíkì ọmọ Húngárì (ib. 1903)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |