Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 9 Oṣù Kàrún
Appearance
- 1994 – Nelson Mandela di Ààrẹ ilẹ̀ Gúúsù Áfríkà
- 2001 – Ní Ghana àwọn alátìlẹ́yìn bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ kú nínú ìjàmbá tí à mọ̀ sí Accra Sports Stadium Disaster.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1927 – Manfred Eigen, German biophysicist
- 1939 – John Ogbu, onímọ̀ ẹ̀dá-ènìyàn ọmọ Nàìjíríà-Amẹ́ríkà (al. 2003)
- 1970 – Ghostface Killah, akọrin rap ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1987 – Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, olóṣèlú ará Nàìjíríà (ib. 1909)
- 1994 – Elias Motsoaledi, alákitiyan ará Gúúsù Áfríkà (ib. 1924)
- 2010 – Lena Horne, akọrin àti òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1917)