Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 9 Oṣù Kọkànlá
Ìrísí
- [[]]
- 1994 – Àkóónú olóògùn Darmstadtium jẹ́ wíwárí.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1731 – Benjamin Banneker (aworan), atòràwọ̀ ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà (al. 1806)
- 1922 – Dorothy Dandridge, akọrin àti òṣeré ará Amẹ́ríkà (al. 1965)
- 1934 – Carl Sagan, olùkọ̀wé àti atòràwọ̀ ará Amẹ́ríkà (al. 1996)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1970 - Charles de Gaulle, ologun ati Aare ile Fransi (ib. 1890)
- 1953 – Ọba Abdul Aziz Al-Saud kábíyèsí àkọ́kọ́ ilẹ̀ Saudi Arabia (ib. 1880)
- 1983 – Haruna Ishola, olorin ara Naijiria (ib. 1919)