Jump to content

Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Agbalagba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ

[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àkókò tí a wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni

Ọjọ́rú 25 Oṣù Kejìlá 2024


Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀

[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orúkọ oníṣẹ́ mi ni Àgbàlagbà. Mo jẹ́ aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá láti ǹkan bí ọdún mẹ́jọ sẹ́yìn. Bákan náà ni mo sì jẹ́ Ààrẹ fún ẹgbẹ̀ Yorùbá Wikimedians User Group tí a ń ṣe agbátẹrù fùn Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àìmọye ènìyàn nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ń tọrọ láti di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí mo ṣàkíyèsí wípé a nílò alábòójútó si lòrì Wikipedia Yorùbá. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìbuwọ́lù yín. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 20:07, 20 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)


Jọ̀wọ́ sọ̀rọ̀ tútù tó dára, kí o má sì ṣe kanra. Tí o kò bá mọ oníṣẹ́ tí ó fẹ́ di alábójútó yìí dáradára, Jọ̀wọ́ ṣe àyẹ̀wo àfikún rẹ̀ dáradára kí o tó dási.

  1. Mo faramọ. Billy bindun (ọ̀rọ̀) 10:19, 21 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)
  2. Mo fara mọ. User: Macdanpets 12:32, 21 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)
  3. Mo fara mọ. Ọmọladéabídèmí99 (ọ̀rọ̀)
  4. Mo faramọ. Ènìyàn yìí ti jẹ́ olùkọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n, ó sì jẹ́ orísun ìwúrí ńláǹlà sí WikipediaToyosi praise (ọ̀rọ̀) 08:19, 23 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)
  5. Mo faramọ Sharon Adeseyoju (ọ̀rọ̀) 08:34, 23 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)
  6. Mo faramọAdeseyoju Deborah (ọ̀rọ̀) 08:41, 23 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)
  7. Mo fara mọ Marvelousola01 (ọ̀rọ̀) 23:39, 23 Oṣù Kẹta 2024 (UTC)
  8. Mo faramọ wípé kí oníṣẹ́ Agbalagba ó fi alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí wípé ó jẹ́ olùfarajìn fún iṣẹ́ àkànṣe náà láti ọdún tí ó ti pẹ́. Ẹ ṣeun Bibiire1 (ọ̀rọ̀) 09:19, 2 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)

Pa cache ojú ewé rẹ́ tí àwọn ìforúkosílẹ̀ kó bá dé ojú ìwọ̀n.