Wolfgang Pauli
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Wolfgang Ernst Pauli)
Wolfgang Pauli | |
---|---|
Ìbí | Wolfgang Ernst Pauli 25 Oṣù Kẹrin 1900 Vienna, Austria-Hungary |
Aláìsí | 15 December 1958 Zürich, Switzerland | (ọmọ ọdún 58)
Ará ìlẹ̀ | Switzerland |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Austria |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Göttingen University of Copenhagen University of Hamburg ETH Zürich Princeton University |
Ibi ẹ̀kọ́ | Ludwig-Maximilians University |
Doctoral advisor | Arnold Sommerfeld |
Other academic advisors | Max Born |
Doctoral students | Nicholas Kemmer Felix Villars |
Other notable students | Sigurd Zienau |
Ó gbajúmọ̀ fún | Pauli exclusion principle Pauli-Villars regularization Pauli matrices Pauli effect Pauli equation Pauli group Coining 'not even wrong' |
Influences | Ernst Mach Carl Jung |
Influenced | Ralph Kronig |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Lorentz Medal (1931) Nobel Prize in Physics (1945) Matteucci Medal (1956) Max Planck Medal (1958) |
Religious stance | Roman Catholic |
Notes His godfather was Ernst Mach. He is not to be confused with Wolfgang Paul, who Pauli called his 'real part.' |
Wolfgang Ernst Pauli (April 25, 1900 – December 15, 1958) je ara orile-ede Ostria to je onimo fisiyiki oniriro ati ikan ninu awon asiwaju ninu fisiyiki ayosere. Ni odun 1945, leyin ti Albert Einstein ti filoruko re sile, o gba Ebun Nobel ninu Fisiyiki fun "afikun to se koko nipa iwari ofin tuntun Adaba re, opo iyasoto tabi opo Pauli," to jemo iro yiyi, to wa labe idimule elo ati gbogbo Kemistri.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |