Wurld
WurlD | |
---|---|
Image of Sadiq Onifade | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Sadiq Onifade |
Ọjọ́ìbí | Lagos, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2012–present |
Labels | WEAREGVDS |
Associated acts | |
Website | wurldmusic.com |
Sadiq Onifade, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí WurlD, jẹ́ Olórin àti Akọ-Orin Nàìjíríà. Wọ́n bi ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà, WurlD padà lọ sí Atlanta, Georgia láti lépa ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírí rẹ̀ àti láti tẹ orin jáde. Ó pe bátànì orin tirẹ̀ ní ẹlẹtiro-fúíṣọ̀nì.[1] Ó kọ EP rẹ̀ àkọ́kọ́ tó pè ní Evolution ní ọdún 2013.[2]
Ìgbẹ́sí ayé rẹ̀ lórí orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ìgbẹ̀yìn ọdún 2012, WurlD kọ orin tuntun , "Beyond Our Dreams" lára EP rẹ̀ àkọ́kọ́ tó pè ní Evolution, ní àsìkò súmà ọdún 2013. Tó jẹ́ ìgbà kan náà pẹ̀lú SESAC tí ó ṣe òde ráńpẹ́ ní ilé-isé wọn ní Atlanta fún EP WurlD tó bọ lọ́nà nígbà náà Evolution EP.[3] Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2013, WurlD wà ní ilé–iṣẹ́ tí wọ́n tí gbórin jáde pẹ̀lú Mario, tí wọn kọ orin fún álíbọ̀mù Olórin náà tó ń bọ̀ lọ́nà. Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, vídíò orin kejì fún álíbọ̀mù Evolution tí ó ń jẹ́, "Alive", tó jẹ́ dídarí láti ọwọ́ Black Shield Entertainment producer Hood Beatz, jáde fún ìgbà àkọ́kọ́ lórí MTV.
Àwọn EP
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Title | Album details |
---|---|
Evolution[4] |
|
Love is Contagious[5] |
|
I love girls with Trobul (Wurld & Sarz)[6] |
|
Afrosoul[7][8] |
|
Àwọn orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Chart positions | Album | ||
---|---|---|---|---|---|
US | UK | POL | |||
2012 | "Beyond Our Dreams" | — | — | — | Evolution (EP) |
2013 | "Alive" | — | — | — | |
"All Night" (Gromee song) | — | — | — | — | |
2015 | "Follow You" (Gromee song) | — | — | 11 | Chapter One |
"Who Do You Love" (Gromee song) | — | — | — | ||
"Summer Yours" | — | — | — | — | |
2016 | "Show You Off" (ft. Shizzi & Walshy Fire) | — | — | — | — |
2017 | "All Night 2017" (Gromee song) | — | — | — | Chapter One |
"Mother's Prayer" | — | — | — | — | |
"All I Need" | — | — | — | — | |
2018 | "Trobul" | — | — | — | I LOVE GIRLS WITH TROBUL
(EP) |
Àwọn orin tó ti fara hàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Other performer(s) | Album |
---|---|---|---|
2013 | "Beautiful Girls" | BK Brasco | TBA |
2015 | "Let You Go" | Leriq | The Lost Sounds |
Netflix n Chill | B.O.B & London Jae | ||
2016 | "Fantasies" | B.O.B & Scotty ATL | The Cooligan |
"Let It Rain" | B.O.B & Scotty ATL | Live & Direct | |
Better Days | Sir Felix | ||
$till Aware | Trinidad James & Scotty ATL | ||
2017 | I Know | B.O.B | Ether |
Fake Friends | B.O.B | ||
2019 | Sweet in the middle | Davido & Naira Marley & Zlatan Ibile | A Good Time |
Àwọn oyè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Event | Prize | Recipient | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2019 | The Headies | Best Vocal Performance (Male) | "Wishes and Butterflies" | Gbàá | [9] |
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [9] | ||||
Hip Hop World Revelation | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [9] |
Ìtọ́kaṣí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Polonsky, Sarah (8 April 2013). "Meet Rising Electro-Fusion Artist WurlD". Vibe. Retrieved 8 June 2013.
- ↑ Brooks, Reginald. "This Is Wurld! Rising Recording Artist Talks About Introducing His Music to the World". The IMC Magazine. Archived from the original on 22 December 2015. Retrieved 8 June 2013.
- ↑ "SESAC Atlanta Hosts Wurld Listening Party". SESAC. 28 September 2012. Retrieved 8 June 2013.
- ↑ "Evolution EP". myspace.com. Retrieved 18 March 2018.
- ↑ "WurLD's Love is Contagious EP". thenativemag.com. Retrieved 24 September 2019.
- ↑ "Sarz & WurlD - I Love Girls With Trobul (EP) | Download « NotJustOk". Latest Naija Nigerian Music, Songs & Video - Notjustok (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-11-08. Archived from the original on 9 August 2020. Retrieved 2020-05-21.
- ↑ "FULL EP: WurlD - Afrosoul (EP) | Download « NotJustOk". Latest Naija Nigerian Music, Songs & Video - Notjustok (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-15. Archived from the original on 24 September 2020. Retrieved 2020-05-21.
- ↑ "Sarz & WurlD "Mad" | Download « Jamsbase". Jamsbase.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-11-01. Retrieved 2019-11-01.
- ↑ 9.0 9.1 9.2 "Headies 2019: Here is the full list of nominees – Pulse Exclusive". PulseNG. Retrieved 10 October 2019.
- ↑ "Timbaland Presents – BKBrasco featuring Wurld "Beautiful Girls"". The Source. 25 April 2013. Retrieved 8 June 2013.