Jump to content

Ìpínlẹ̀ Missouri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
State of Missouri
Flag of Missouri State seal of Missouri
Àsìá Èdìdí
Ìlàjẹ́: The Show-Me State (unofficial)
Motto(s): Salus populi suprema lex esto (Latin)
Map of the United States with Missouri highlighted
Map of the United States with Missouri highlighted
Èdè oníibiṣẹ́ English
Orúkọaráàlú Missourian
Olúìlú Jefferson City
Ìlú atóbijùlọ Kansas City
Largest metro area Greater St Louis Area[1]
Àlà  Ipò 21st ní U.S.
 - Total 69,704 sq mi
(180,533 km2)
 - Width 240 miles (385 km)
 - Length 300 miles (480 km)
 - % water 1.17
 - Latitude 36° N to 40° 37′ N
 - Longitude 89° 6′ W to 95° 46′ W
Iyeèrò  Ipò 18th ní U.S.
 - Total 5,911,605 (2008 est.)[2]
5,595,211 (2000)
Density 85.3/sq mi  (32.95/km2)
Ranked 28th in the U.S.
 - Median income  $45,114 (37st)
Elevation  
 - Highest point Taum Sauk Mountain[3]
1,772 ft (540 m)
 - Mean 800 ft  (240 m)
 - Lowest point St. Francis River[3]
230 ft (70 m)
Admission to Union  August 10, 1821 (24th)
Gómìnà Eric Greitens (R)
Ìgbákejì Gómìnà Mike Parson (R)
Legislature {{{Legislature}}}
 - Upper house {{{Upperhouse}}}
 - Lower house {{{Lowerhouse}}}
U.S. Senators Roy Blunt (R)
Claire McCaskill (D)
U.S. House delegation 5 Republicans, 4 Democrats (list)
Time zone Central : UTC-6/-5
Abbreviations MO US-MO
Website mo.gov

Missouri je Ipinle kan ni ile Amerika. Aarin gbungbun iwo-oorun ile Amerika ni ipinle yii wa.. Oke kan ti o n je Ozark Mountain wa nibe. Ibe naa ni omi kan ti o n je Missouri wa. Apapo omi Missouri yii ati Mississippi ni odo ti o gun ju ni agbaye. Ile-ise po ni ipinle tii. Awon eniyan ti o n gbe ibe to 4,667,000. Jefferson City ni olu-ilu Missouri sugbon St. Louis ati Kasas City ni awon ilu ti o tobi ju nibe. Awon ile Faranse ni o gba Missouri 1673 ati 1682. Awon ile Amerika gba a ni 1803 o si di ipinle ni 1821. ninu ogun abel ile Amerika, awon Union ni Missouri ja fun.

Àwọn ìtọ́kaśi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. http://www.census.gov/population/cen2000/phc-t29/tab03b.xls U.S. Census 2000 Metropolitan Area Rankings; ranked by population
  2. "Annual Estimates of the Resident Population for the United States, Regions, States, and Puerto Rico: April 1, 2000 to July 1, 2008". United States Census Bureau. Retrieved 2009-01-31. 
  3. 3.0 3.1 "Elevations and Distances in the United States". U.S Geological Survey. April 29, 2005. Archived from the original on June 1, 2008. Retrieved November 6 2006.  Unknown parameter |dateformat= ignored (help); Check date values in: |access-date= (help)