Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Nnewi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
No edit summary
Ìlà 8: Ìlà 8:
{{Reflist}}
{{Reflist}}


5. https://www.manpower.com.ng/places/lga/121/nnewi-south






Àtúnyẹ̀wò ní 21:55, 16 Oṣù Bélú 2019

Àgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi jẹ́ ọ̀kan lára ìjọba-ìbílẹ̀ mọ̀kànlélógún tí ó wà Ìpínlẹ̀ Anambra ní orílè-èdè Nàìjíríà.[1] Ìlú Ukpor ni Olú-ìlú ìjọba-ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi.[2] Wọ́n dá a sílẹ̀ ní ọdún 1991 pẹ̀lú àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mọ̀kànlélógún yòókù.[3] Àwọn olùgbé ìjọba-ìbílẹ̀ náà tó mílíọ́nù kan.

Àwọn gbajúmọ̀ ìlú tí wọ́n wà ní ìjọba ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi

Yàtọ̀ sí olú-ìlú ìjọba ìbílẹ̀ náà, àwọn ìlú gbajúmọ̀ tí wọ́n tún wà lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi ni; Ekwulumili, Amichi, Azigbo, Unubi, Ezinifite, Osumenyi àti Utuh. [4]

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. Kabir, Olivia (2018-12-21). "Local governments in Anambra state and their towns". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-11-16. 
  2. "Light Of The Nation". Anambra State Government. Retrieved 2019-11-16. 
  3. "History of Anambra state". Oganiru Anambra. 2019-11-12. Retrieved 2019-11-16. 
  4. "Nnewi South L.G.A List of towns and villages". Nigeria Zip Codes (in Èdè Ruwanda). Retrieved 2019-11-16. 

5. https://www.manpower.com.ng/places/lga/121/nnewi-south