Kọ́lá Òyéwọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Macdanpets (ọ̀rọ̀ | àfikún) →Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀: New Page Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit |
Macdanpets (ọ̀rọ̀ | àfikún) No edit summary Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit |
||
Ìlà 1: | Ìlà 1: | ||
'''Kọ́lá Òyéwọ̀''' (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1946) jẹ́ àgbà òṣèré sinimá àgbéléwò àti olùkọ́ ilé ìwé Ifáfitì ọmọ orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]]. Ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò lóríṣiríṣi. Sinimá kan gbòógì tó gbé ìràwọ̀ rẹ̀ jáde ní "Orogún Adédigba" Bí ó ṣe ń ṣiṣẹ́ tíátà náà ló ń ṣíṣe olùkọ́. Ó ti jẹ́ olùkọ́ ní ifáfitì Ọbáfẹ́mi Awolọ́wọ̀ tí wọ́n ń pè ní [[Obafemi Awolowo University]], O.A.U., ní [[Ilé-Ifẹ̀]], [[Redeemer's University]], ní ìlú Ọ̀tà ní ìpínlẹ̀ Ògùn, bẹ́ẹ̀ náà ní [[Elizade University]] Ilara-Mokin, ní ìpínlẹ̀ Oǹdó. |
'''Kọ́lá Òyéwọ̀''' (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1946) jẹ́ àgbà òṣèré sinimá àgbéléwò àti olùkọ́ ilé ìwé Ifáfitì ọmọ orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]]. Ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò lóríṣiríṣi. Sinimá kan gbòógì tó gbé ìràwọ̀ rẹ̀ jáde ní "Orogún Adédigba" Bí ó ṣe ń ṣiṣẹ́ tíátà náà ló ń ṣíṣe olùkọ́. Ó ti jẹ́ olùkọ́ ní ifáfitì Ọbáfẹ́mi Awolọ́wọ̀ tí wọ́n ń pè ní [[Obafemi Awolowo University]], O.A.U., ní [[Ilé-Ifẹ̀]], [[Redeemer's University]], ní ìlú Ọ̀tà ní ìpínlẹ̀ Ògùn, bẹ́ẹ̀ náà ní [[Elizade University]] Ilara-Mokin, ní ìpínlẹ̀ Oǹdó.<ref name="Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria 1946">{{cite web | title=Kola Oyewo biography, net worth, age, family, contact & picture | website=Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria | date=1946-03-27 | url=https://www.manpower.com.ng/people/15968/kola-oyewo | access-date=2019-11-29}}</ref> <ref name="The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News">{{cite web | title=Kola Oyewo Archives - Nigeria and World News | website=The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News | url=https://m.guardian.ng/tag/kola-oyewo/ | access-date=2019-11-29}}</ref> |
||
==Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀== |
==Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀== |
Àtúnyẹ̀wò ní 10:45, 29 Oṣù Bélú 2019
Kọ́lá Òyéwọ̀ (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1946) jẹ́ àgbà òṣèré sinimá àgbéléwò àti olùkọ́ ilé ìwé Ifáfitì ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò lóríṣiríṣi. Sinimá kan gbòógì tó gbé ìràwọ̀ rẹ̀ jáde ní "Orogún Adédigba" Bí ó ṣe ń ṣiṣẹ́ tíátà náà ló ń ṣíṣe olùkọ́. Ó ti jẹ́ olùkọ́ ní ifáfitì Ọbáfẹ́mi Awolọ́wọ̀ tí wọ́n ń pè ní Obafemi Awolowo University, O.A.U., ní Ilé-Ifẹ̀, Redeemer's University, ní ìlú Ọ̀tà ní ìpínlẹ̀ Ògùn, bẹ́ẹ̀ náà ní Elizade University Ilara-Mokin, ní ìpínlẹ̀ Oǹdó.[1] [2]
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
Wọ́n bí Olóyè Kọ́lá Òyéwọ̀ sí ìlú Ọ̀bà-Ilé ni ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lỌjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1946. Àkọsílẹ̀ nípa ẹ̀kọ́ ìgbà èwe rẹ̀ farasin, ṣùgbọ́n ó kàwé gboyè nínú iṣẹ́ tíátà àti lítíréṣọ̀ a lóhùn èdè Yorùbá ní ifáfitì Ọbáfẹ́mi Awolọ́wọ̀ ní Ilé-Ifẹ̀ lọ́dún 1995. Ó tẹ̀ síwájú ní ifáfitì ìlú Ìbàdàn níbi tí ó ti kàwé gboyè dìgírì kejì àti oyè ọ̀mọ̀wé dọ́kítà nínú iṣẹ́ tíátà
Àtòjọ àwọn sinimá àgbéléwò tí Kọ́lá Òyéwọ̀ tí kópa
- Sango (1997)
- Super Story (episode 1)
- The Gods Are Not To Blame
- Saworo Ide
- Koseegbe (1995
- ↑ "Kola Oyewo biography, net worth, age, family, contact & picture". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. 1946-03-27. Retrieved 2019-11-29.
- ↑ "Kola Oyewo Archives - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2019-11-29.