Àkàrà
Acarajé in Salvador, Brazil | |
Alternative names | Acara, Àkàrà, Kosai |
---|---|
Course | Street-food |
Place of origin | West Africa |
Region or state | West Africa and South America |
Associated national cuisine | Nigeria, Ghana, Togo, Benin, Mali, Gambia and Brazil |
Serving temperature | Hot |
Main ingredients | Black eyed peas, deep-fried in dendê (palm oil) |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Àkàrà jẹ́ oúnjẹ abínibí ìbílẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá àti púpọ̀ nínú ilẹ̀ Adúláwọ̀.
Ṣíṣe àkàrà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkàrà wà nínú àrà tí wọ́n ma ń fi ẹ̀wà dá. Wọ́n ma ń rẹ ẹ̀wà sínú omi, fún bii ọgbọ̀n ìṣẹ́jú tàbí wákàtí kan kí ó lè rọ̀. Lẹ́yìn èyí, wọn yóò fi ata, àlùbọ́sà, edé àti àwọn nkan mìíràn tí ó bá wù wá si kí wọ́n tó lọ̀ọ́ kúná. Lẹ́yìn tí wọ́n bá lọ̀ọ́ tán, wọn yóò gbé epo tàbí òróró kaná tí wọn yóò sì ma dá ẹ̀wà náà sínú epo yí kí ó lè dín.[1][2]
Bí wọ́n ṣe ń jẹ àkàrà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n lè jẹ àkàrà lásán, wọ́n lè fi jẹ̀kọ, jẹ búrẹ́dì, mùkọ, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[3]
Ṣíṣaara lóore
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Akara ní àwọn èròjà láti múni sanra, torí àwọn èròjà proteins, vitamins àti minerals bí i calcium, iron àti zinc inú rẹ̀.[4][5] Àmọ́ ṣáá, àwọn èròjà inú rẹ̀ lè ti dínkù nítorí àwọn àfikún kan bí iphytates, fibers, lectins, polyphenols àti tannins tí kì í ṣe ara lóore.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Akara Nigerian Breakfast Recipe". All Nigerian Recipes. 2019-03-24. Retrieved 2019-12-18.
- ↑ Lete, Nky Lily (2013-02-23). "Nigerian Akara Recipe: How to Make Akara". Nigerian Food TV. Retrieved 2019-12-18.
- ↑ "How To Make Akara (Bean Cakes) - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2017-09-30. Retrieved 2019-12-18.
- ↑ 4.0 4.1 Almeida, Deusdélia T.; Greiner, Ralf; Furtunado, Dalva M. N.; Trigueiro, Ivaldo N. S.; Araújo, Maria da Purificação N. (2008-01-24). "Content of some antinutritional factors in bean cultivars frequently consumed in Brazil: Antinutrients in beans" (in en). International Journal of Food Science & Technology 43 (2): 243–249. doi:10.1111/j.1365-2621.2006.01426.x.
- ↑ Carvalho, Ana Fontenele Urano; de Sousa, Nathanna Mateus; Farias, Davi Felipe; da Rocha-Bezerra, Lady Clarissa Brito; da Silva, Renata Maria Pereira; Viana, Martônio Ponte; Gouveia, Sandro Thomaz; Sampaio, Silvana Saker et al. (2012-05-01). "Nutritional ranking of 30 Brazilian genotypes of cowpeas including determination of antioxidant capacity and vitamins" (in en). Journal of Food Composition and Analysis 26 (1): 81–88. doi:10.1016/j.jfca.2012.01.005. ISSN 0889-1575.