Ata
Appearance
Ata ni ohun èso tí a ká tí a sì fi pèsè yálà ohun jíjẹ bí Ọbẹ̀ tàbí mímu mìíràn kí ó le ta lẹ́nu kí ó sì lè ṣe ànfàní fún ará. Pàá pàá jùlọ lásìkò òtútù tàbí ọ̀gìnìntìn. [1][2]
Oríṣi ata to wà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ata rodo
- Ata ṣọ̀mbọ̀
- Ata gbígbẹ
- Ata ilẹ̀
- Ata Tàtàṣé
- Tìmọ́ọ̀tì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [3][4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "pepper - meaning of pepper in Longman Dictionary of Contemporary English". LDOCE. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ Reid, Robert (2020-01-15). "The world’s most prized pepper?". BBC. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ Onyeakagbu, Adaobi (2019-09-06). "The different types of peppers we have in Nigeria". Pulse Nigeria. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ BM, Myers; Al., Et. "Effect of red pepper and black pepper on the stomach.". NCBI. Retrieved 2020-01-19.