Ọbẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Ọbẹ̀
A Hungarian goulash soup
TypeSoup
Main ingredientsLiquid (stock, juice, water), meat or vegetables or other ingredients
VariationsClear soup, thick soup
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Ọbẹ̀ ni ohun jíjẹ tí a fi oríṣiríṣi ohun èlò ìsebẹ̀ pèsè, láti fi jẹun lájẹ gbádùn. Ọbẹ̀ ni ó ṣeé jẹ ní gbígbóná tàbí kí ó lọ́ wọ́ọ́rọ́, a sì lè jẹẹ́ ni tútù pẹ̀lú.[1]

Àwọn èròjà ọbẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lílo èròjà ọbẹ̀ dá lórí irúfẹ́ ọbẹ̀ tí a bá fẹ́ sè. Díẹ̀ lára àwọn èròjà ọbẹ̀ ni :

Oríṣi ọbẹ̀ tó wà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó yẹ kí a pààlà rẹ̀ wípé oríṣiríṣi ọbẹ̀ lò wà ní oríṣiríṣi ìlú tàbí ilẹ̀ àgbáyé, kódà ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ pàá pàá jùlọ ní ilẹ̀ Yorùbá. Ọbẹ̀ sísè dá lórí bí ìlú tàbí àwọn ènìyàn ibẹ̀ bá ṣe gbáfẹ́ nípa ónjẹ sí ni. Díẹ̀ lara àwọn ọbẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá ni :

[3][4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Different Types of Soups in Nigeria". All Nigerian Foods. 2012-09-06. Retrieved 2020-01-20. 
  2. Cavoto, Erin; Cavoto, Erin; Cavoto, Erin (2020-01-03). "50+ Best Soup Recipes - Easy Homemade Recipes for Soup". Country Living. Retrieved 2020-01-20. 
  3. "Soup". BBC Good Food. 2013-05-28. Retrieved 2020-01-20. 
  4. Goltz, Eileen (9 November 2008). "Soup vs. stew: Difference in details". The Journal Gazette (Fort Wayne, Indiana). Archived from the original on 11 August 2011. Retrieved 6 March 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)