Jump to content

Àtòjọ Àwọn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà Nípa Bi Wọ́n Ṣe Pọ̀ Tó Níye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Èyí ni Àtòjọ Àwọn Orílẹ̀-èdè Àfíríkà Nípa Bí Wọ́n Ṣe Pọ̀ Tó Níye, a kọ èyí sílẹ̀ nípa lílo ìwòye iye ènìyàn tí ó wà lórílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú Ìtọ́kasí ètò ìkànìyàn tí wọ́n ṣe lẹ́yìn lórílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan. Láìsí àní-àní, ilẹ̀ Áfíríkà ṣì ní ilẹ̀ tí ó ń dàgbà jùlọ níye ènìyàn ní gbogbo àgbáyé lẹ́yìn ilẹ̀ Asia. [1] Ìdá ọgọ́ta (60%) àwọn ènìyàn Áfíríkà ní wọ́n wà ní ọmọ ọjọ́ orí mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n tàbí kéré sí iye ọjọ́ orí yẹn sí ọjọ́ orí wọn,[2] èyí wá mú kí ṣíṣe àtẹ ìdàgbàsókè iye ènìyàn tí ó wà lórílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan dá lé bí ètò ìṣèjọba àti ìdàgbàsókè ètò ọ̀rọ̀-ajé ṣe ṣe pàtàkì tó.

Rank Country
(or dependent territory)
Official
figure
(where
available)
Date of
last figure
Source
1 Nàìjíríà Nàìjíríà 200,963,599 2019 Worldometers[3]
2  Ethiopia 112,078,730 2019 Worldometers
3  Egypt 99,919,467 January 25, 2020 Official population clock
4  Democratic Republic of the Congo 86,026,000 July 1, 2019 Official estimate
5  Gúúsù Áfríkà 58,775,022 July 1, 2019 Official estimate
6  Tanzania 51,046,000 2015 Official estimate
7  Kenya 47,564,296 2019 Official estimate
8  Algeria 43,000,000 January 1, 2019 Official estimate
9 Àdàkọ:SDN 42,268,269 January 25, 2020 Official population clock Archived 2020-05-11 at the Wayback Machine.
10 Àdàkọ:MAR 35,795,289 January 25, 2020 Official population clock Archived 2021-05-13 at the Wayback Machine.
11 Àdàkọ:UGA 34,634,650 August 28, 2014 Official estimate
12 Àdàkọ:MOZ 28,013,000 2015 Official estimate
13  Ghana 27,043,093 2014 Official estimate
14 Àdàkọ:ANG 24,383,301 May 16, 2014 Preliminary 2014 census result
15  Côte d'Ivoire 22,671,331 May 15, 2014 Preliminary 2014 census result
16 Àdàkọ:MDG 22,434,363 2014 Official estimate
17  Cameroon 21,917,602 2015 Official estimate Archived 2018-05-17 at the Wayback Machine.
18  Niger 17,138,707 December 10, 2012 Final 2012 census result
19 Bùrkínà Fasò Bùrkínà Fasò 18,450,494 2015 Official estimate
20  Mali 14,528,662 April 1, 2009 Final 2009 census result
21  Màláwì 16,832,900 July 1, 2016 Official estimate
22 Àdàkọ:ZAM 15,473,905 2015 Official estimate
23  Somalia 12,316,895 January 1, 2016 Official estimate
24 Àdàkọ:SEN 14,354,690 2015 Official estimate
25  Chad 11,039,873 May 20, 2009 Final 2009 census result
26 Àdàkọ:ZIM 13,061,239 August 17, 2012 Final 2012 census result
27 Àdàkọ:RWA 10,515,973 August 15, 2012 Final 2012 census result
28  Tunisia 10,982,754 April 23, 2014 Preliminary 2014 census result
29  Guinea 10,628,972 April 2, 2014 Preliminary 2014 census result Archived 2012-07-12 at the Wayback Machine.
30  Benin 10,008,749 May 11, 2013 Final 2013 census result
31  Burundi 9,823,828 2015 Official estimate Archived 2019-04-03 at the Wayback Machine.
32 Àdàkọ:SSD 8,260,490 April 22, 2008 2008 census result
33  Togo 6,191,155 November 6, 2010 Final 2010 census result
34  Ẹritrẹ́à 6,536,000 July 1, 2014 Official estimate
35 Àdàkọ:SLE 6,348,350 2014 Official estimate
36 Àdàkọ:LBY 5,298,152 April 15, 2006 2006 census result
37  Republic of the Congo 3,697,490 April 28, 2007 2007 census result
38  Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Áfríkà 3,859,139 2017 [1]
39 Àdàkọ:LBR 3,476,608 March 21, 2008 Final 2008 census result
40 Àdàkọ:MTN 3,718,678 2016 Official estimate
41  Namibia 2,280,700 July 1, 2015 Official estimate
42 Àdàkọ:BOT 2,024,904 August 22, 2011 Final 2011 census result Archived 2013-05-25 at the Wayback Machine.
43 Àdàkọ:LES 1,894,194 2011 Official estimate Archived 2014-11-13 at the Wayback Machine.
44  Gambia 1,882,450 April 15, 2013 Preliminary 2013 census result[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
45  Gabon 1,802,278 October 5, 2013 Preliminary 2013 census result
46 Àdàkọ:GNB 1,530,673 2015 Official estimate
47 Àdàkọ:MRI 1,261,208 July 1, 2014 Official estimate
48  Guinea Alágedeméjì 1,222,442 July 4, 2015 Preliminary 2015 census result
49  Eswatini 1,119,375 2015 Official estimate
50  Djìbútì 864,618 July 1, 2011 Official estimate
Àdàkọ:REU (France) 840,974 January 1, 2013 Official estimate
51  Kòmórò 806,200 July 1, 2016 Official estimate
52  Cape Verde 491,875 June 16, 2010 Final 2010 census result[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
Western Sahara[4] 510,713 September 2, 2014 Preliminary 2014 census result
Àdàkọ:MYT (France) 212,600 August 21, 2012 2012 census result
53 Àdàkọ:STP 201,784 2018 Official estimate Archived 2019-01-24 at the Wayback Machine.
54 Àdàkọ:SEY 90,945 August 26, 2010 Final 2010 census result
Àdàkọ:SHN (UK) 5,633 June 2016 2016 census result

Àdàkọ:Pie chart

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-03-08. Retrieved 2020-02-05. 
  2. https://www.un.org/esa/socdev/documents/youth/fact-sheets/YouthPOP.pdf
  3. "African countries by population (2019)". Retrieved 15 September 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Administration is split between Morocco and the Sahrawi Arab Democratic Republic, both of which claim the entire territory.