Àwọn ọbẹ̀
Ìrísí
Orúkọ | Àwòrán | Orírun | Tradional protein | Àpèjúwe àti àwọn ohun èlò | ||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Gaisburger Marsch | Germany (Swabia) |
ẹran màálù | oúnjẹ àwọn Swabian tí wọ́n ṣe láti ara ẹran àti ànàmọ́ ṣíṣè àti spätzle. | |||||
Galinhada | Brazil | Fowl | ọbẹ̀ ìrẹsì àti ṣíkìn | |||||
Garbure | France (Gascony) |
ẹran ẹlẹ́dẹ̀ | Ọbẹ̀ ham pẹ̀lú cabbage àti àwọn ẹ̀fọ́ mìíràn | |||||
Ghapama | Armenia | Vegetarian | Ọbẹ̀ yìí kì í ní ẹran nínú | |||||
Gheimeh | Iran | ọmọ ẹran àgùntàn | ọbẹ̀ ẹran àgùntàn gígé nígbà mìíràn ó lè jẹ́ ẹran màálù. Wọ́n sáábà máa ń jẹ ọbẹ̀ yìí pẹ̀lú ìrẹsì funfun. | |||||
Ghormeh sabzi | Iran | Vegetarian (ṣùgbọ́n tí wọ́n máa ń ṣe pẹ̀lú ẹran nígbà mìíràn) | Ọbẹ̀ tí a fi egbò àti ẹ̀fọ́ sè | |||||
Goat water | Montserrat | Ewúrẹ́ | Oúnjẹ gbogboogbò ti Montserrat èyí tí wọ́n máa ń sè pẹ̀lú ẹran ewúrẹ́ àti ẹ̀fọ́ | |||||
Goulash | Hungary | Ẹran màálù | Ọbẹ̀ ẹran màálù pẹ̀lú ẹ̀fọ́ àti àwọn èròjà mìíràn | |||||
Guatitas | Chile Ecuador |
Offal | Ọbẹ̀ tí ó jẹ́ pé èròjà rẹ̀ jẹ́ ìfun | |||||
Guiso carrero | Argentina Uruguay |
Ẹran màálù | Ọbẹ̀ ìbílẹ̀ tí a máa ń sè pẹ̀lú ẹran màálù, chorizoh, ẹ̀wà funfun, chickpeas, ànàmọ́, kárọ́ọ̀tì, àlùbọ́sà. | |||||
Gumbo | United States (Louisiana) |
Seafood àti sausage | Ọbẹ̀ tí ó kún fún ata àti àlùbọ́sà | |||||
Güveç | Turkey | ọmọ ẹran àgùntàn | Ọbẹ̀ ẹran àti ẹ̀fọ́, èyí tí ó gbajúmọ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè Balkan. | |||||
Guyana Pepperpot | Guyana | Various | Ọbẹ̀ ẹran àti ata, a lè lo ẹran ṣíkìn pẹ̀lú | |||||
Hachee | Netherlands | Various | Ọbẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn Dutch tó dá lórí ẹran gígé, ẹja, tàbí ẹran adìẹ, àti ẹ̀fọ́. | |||||
Hamin | Iberia | Àgùntàn, ẹran màálù, tàbí ṣíkìn | Ọbẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn Jewish tí wọ́n máa ń jẹ fún Sabbath wọ́n máa ń sè é mọ́jú. Èyí tí a tún mọ̀ sí dafina. | |||||
Hasenpfeffer | Germany | Ẹran ìgbẹ́ | Ọbẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn German tí wọ́n ṣe láti ara ẹran ehoro. | |||||
Hochepot | France | Ẹran màálù | Ọbẹ̀ Flemish tí wọ́n sè láti ara oxtail àti àwọn ẹ̀fọ́ | |||||
Hoosh | United States | Ẹran màálù (gbígbẹ) | Ọbẹ̀ kíkì tí wọ́n sè pẹ̀lú ẹran màálù | |||||
Hot pot | China Taiwan Mongolia |
Various | Ọbẹ̀ tí wọ́n sè pẹ̀lú onírúurú ẹran. | |||||
Irish stew | Ireland | Àgùntàn | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran àgùntàn | |||||
Islim or patlıcan kebabı | Turkey | Ẹran àgùntàn | Ọbẹ̀ ẹran pẹ̀lú àwọn ata | |||||
Istrian stew | Croatia | Ẹlẹ́dẹ̀ | Ọbẹ̀ tí àwọn èròjà rẹ̀ jẹ́ ẹ̀wà, sauerkraut, ànàmọ́, bacon, àti àwọn èròjà mìíràn | |||||
Jjigae | Korea | Various | Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú àwọn ẹran àti oríṣiríṣi ata.[1] | |||||
Jugged hare | France United Kingdom |
ẹran ìgbẹ́ | Ọbẹ̀ tí a pèèlò pẹ̀lú ẹran ehoro gẹ́gẹ́ bíi èròjà tí ó ṣe kókó | |||||
Kadyos, bay, kag langka | Philippines | Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ | Pigeon peas, ham hock, àti [[jackfruit] (Garcinia binucao)[2] | |||||
Kadyos, manok, kag ubad | Philippines | Fowl | Pigeon peas, [[ṣíkìn], àti ọ̀gẹ̀dẹ̀ [3][4] | |||||
Kaldereta | Philippines | Ẹran ewúrẹ́ | Ọbẹ̀ tí èròjà rẹ̀ jẹ́ apá ẹran ewúrẹ́ pẹ̀lú tòmátò àti ẹ̀dọ̀ ewúrẹ́
Nm |
Philippines | Ẹran màálù | ọbẹ̀ ẹran màálù tí a sè pẹ̀lú ẹ̀pà àti àwọn èròjà mìíràn | ||
Karelian hot pot | Finland | Ẹran màálù àti ẹran ẹlẹ́dẹ̀ | Wọ́n máa ń ṣe ọbẹ̀ yìí pẹ̀lú ẹran màálù àti ẹran ẹlẹ́dẹ̀ pẹ̀lú àwọn èròjà mìíràn |
- ↑ Àdàkọ:In lang Jjigae[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] at Doosan Encyclopedia
- ↑ "It's Time You Know about Kadios beyond KBL". Pepper.ph. Retrieved 8 February 2021.
- ↑ "Manok at Kadyos / Purple Chicken With Pigeon Peas". Market Manila. 21 October 2007. Retrieved 8 February 2021.
- ↑ "Kadyos Beans". Ark of Taste. Slow Food Foundation for Biodiversity. Retrieved 8 February 2021.