Èdè Wolof

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Wolof
Sísọ ní

 Sẹ̀nẹ̀gàl  Gámbíà

 Mauritáníà
Agbègbè West Africa
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀

3.2 million (mother tongue)

3.5 million (second language) [1]
Èdè ìbátan
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ ní Kòsí
Àkóso lọ́wọ́ CLAD (Centre de linguistique appliquée de Dakar)
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1 wo
ISO 639-2 wol
ISO 639-3 either:
wol – Wolof
wof – Gambian Wolof

Ede Wolof je èdè tí à ń so ni atí bèbè Senegal Mílíònù méjì-àbò niye àwon tó ń so. Awon Olùbágbè won ni Mandika ati Fulaní. Awon isé ona won màa ń rewà tó sì ma ń ní àmìn àti àwòràn àwon asáájú nínú èsìn musulumi. Ìtan Wolof ti wà láti bí egbèrún odún méjìlá tàbí métàlá séyìn. Ìtàn ebí alátenudénu won so pé òkan lára àwon tó koko tèdó síbí yìí jé awon to wa láti orífun Fulbe. Òpòlopò ìtàn Wolof ni a le rí nínú àwon orin oríkì èyí ti a ma ń gbó láti enu àwon ‘Griots’ àwon akéwì. Mùsùlùmí ni òpòlopò àwonm ará Wolof.


  1. Gordon, Raymond G., Jr. (ed.), 2005. Ethnologue: Languages of the World, Fifteenth edition. Dallas, Tex.: SIL International. Online version: http://www.ethnologue.com/, wolof entry here