Jump to content

Ẹ̀gbá Aké

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ègbá Aké)
Egba Ake

Egba Alake
Egba Ake is located in Nigeria
Egba Ake
Egba Ake
Location in Nigeria
Coordinates: 7°9′39″N 3°20′54″E / 7.16083°N 3.34833°E / 7.16083; 3.34833
Country Nigeria
StateOgun State

Egba Ake, tí a tún mọ̀ sí Ẹ̀gbá Aláké jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ka márààrún tí Ẹ̀gbá pín sí. Àwọn ẹ̀ka yòókù ni Oke-Ona, Gbagura, Owu àti Ibara (ìtàn fi yé wa pé Ibara wà lára Yewa, kì í ṣe Ẹ̀gbá, àmọ́ agbègbè Abẹ́òkúta ni ó wà báyìí. Aláké ti ìlú Ẹ̀gbá ni ọba tàbí olórí gbogbo ẹ̀yà Ẹ̀gbá.[1]

Solomon's knot, a quasi-heraldic symbol of Yoruba royalty

Èyí ni àtòjọ àwọn olórí tàbí adarí Ẹ̀gbá, tó joyè Aláké, láti ọdún 1854[2]

Ìbèrè Òpin Orúkọ Olórí
1829 1845 Shodeke
1845 1846 Shomoye -Regent (1st time)
1846 1854 Sagbua Okukenun -Regent
8 Aug 1854 1862 Okukenun (Sagbua Okukenun) First Alake
1862 1868 Shomoye -Regent (2nd time)
28 Nov 1869 20 Dec 1877 Ademola I
Jan 1879 15 Sep 1881 Oyekan (d. 1881)
9 Feb 1885 27 Jan 1889 Oluwajin
18 Sep 1891 11 Jun 1898 Oshokalu
8 Aug 1898 28 May 1920 Gbadebo I (1854–1920)
27 Sep 1920 27 Dec 1962 Ladapo Samuel Ademola II (1872–1962) (in exile 1948 – 3 Dec 1950)
29 Sep 1963 26 Oct 1971 Adeshina Samuel Gbadebo II (1908–1971)
5 Aug 1972 3 Feb 2005 Samuel Oyebade Mofolorunsho Lipede (1915–2005)
24 Aug 2005 Adedotun Aremu Gbadebo III (b. 1943)[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Niyi Odebode (5 November 2007). "Alake, others fault Owu’s claim on Abeokuta". The Punch. Archived from the original on 5 November 2007. Retrieved 2010-09-07.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Traditional States of Nigeria". WorldStatesmen.org. Retrieved 2010-09-07. 
  3. Niyi Odebode and Olaolu Oladipo (4 August 2005). "Gbadebo emerges new Alake – • We’re yet to confirm any candidate – Ogun govt". Online Nigeria Daily News. Archived from the original on 12 March 2012. Retrieved 3 February 2023.