Ìṣe Òfin àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú 1964
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ìṣe Àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú ti ọdún 1964)
Ìṣe Àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú ti ọdún 1964 je ofin pataki ni orile-ede Amerika ti o fi ofin de iwa eleyameya n'ile eko, n'igboro ati l'enu ise. A da sile lati fi se ranlowo fun awon Ọmọ Afrika Amerika.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |