Ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré
Ìrísí
Ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré jẹ́ àwo róbótó tí ó wà lára ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po, tí ó wà ní bíi àárín ìyípo Mars àti Jupiter. Àwọn àkórajọ onírúurú tí kò dúró déédé tí wọ́n ń pè ní ástẹ́rọ́ìdì tàbí àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré ló gba inú rẹ̀. Wọ́n tún máa ń pe ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré ní ojúlówó ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré tàbí ojúlówó ìgbàjá lati jẹ́ kí ìyàtọ̀ wá láàárín rẹ̀ àti àwọn míràn tí wọ́n wà lágbo ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po bíi Awon asteroidi itosi Aye ati awon asteroidi troja.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Matt Williams (2015-08-23). "What is the Asteroid Belt?". Universe Today. Retrieved 2016-01-30.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
- ↑ "Mars: An Introduction to its Interior, Surface and Atmosphere". Google Books. 1956-07-03. Retrieved 2018-05-15.