Ìlú Festac

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Wood carvings for sale in Festac Town

Ìlú Festac jẹ́ ìlú kan tí ìjọba kọ́ ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ilé-ìgbé sí ní ìpínlẹ̀ Èkó, ìlú yí wà ní òpópónà márosẹ̀ ti Èkó sí Àgbádárìgì. Wọ́n ṣe ìkékúrú orúkọ ibùgbé náà sí (FESTAC)tí àkótán rẹ̀ dúró fún : (Second World African Festival of Arts and Culture), ìyẹn Ọdún àṣà àti ìṣe ti àpapọ̀ ilẹ Adúláwọ̀ tí ó wáyé níbẹ̀ ní ọdún 1977.[1] Ìlú Festac yí wà ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Amúwò-Ọ̀dọ̀fin ní ìpínlẹ̀ Èkó orílè-èdè Nàìjíríà.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]