Jump to content

Ẹ̀kọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ògì)
Ogi
Ogi
Alternative namesAkamu, eko
TypePap tàbí pudding
Place of originNàìjíríà, Kenya, Cameroon
Region or stateìwọ̀ oòrùn Africa
Main ingredientsàgbàdo, ọkà tàbí jéró
Ingredients generally usedsugar
VariationsUji ní Kenya
Àdàkọ:Wikibooks-inline 
Ẹ̀kọ tútù

Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí ó gbajúmọ̀ ní Nàìjíríà, tí wón sì ń fi àgbàdo, ọkà tàbí jéró ṣe.[1][2][3][4] Bí wọ́n bá fẹ́ se ògì, wọ́n á rẹ àgbàdo,, ọkà tàbí jéró sínú omi fún ọjọ́ méjì sí mẹta kí wón tó lọ̀ ọ́, lẹ́yìn náà, wọ́n ọ́ fi kalẹ̀ fún bí í ọjọ́ mẹ́ta mìíràn láti kan, lẹ́yìn èyí, wọ́n le sè é. Wọ́n máa ń fi àkàrà, mọ́ín mọ́ín àti àwọn oúnjẹ míràn mu ẹ̀kọ.

  1. "Fermented Cereals - A Global Perspective". United Nations FAO. Retrieved 2006-07-22. 
  2. "Process of making Ogi (pap, akamu)". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-04-26. Retrieved 2022-06-01. 
  3. Kenzap (2020-07-14). "AKAMU/OGI (PAP)". Diet Tech Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-01. 
  4. "Oloye Corn Meal - Akamu / Pap / Koko/ogi". My Sasun (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-01.