Jump to content

Ẹ̀bà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ẹ̀bà jẹ́ óuńjẹ òkèlè tí wọ́n ma ń jẹ ní apá ilẹ̀ Adúláwọ̀ ati agbègbè rẹ̀ pàá pàá jùlọ ní orílé-èdè Nàìjíríà àti Gánà. Ẹ̀bà ni àwọn ẹ̀yà Yorùbá sábà ń pèé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1]O jé ounjẹ sítáàṣì ewébẹ̀ tí wọ́n ti sè láti inú iṣu Ègé gbìgbẹ tí wọ́n ti bè, ti wọ́n sábà máa mọ̀ sí gàrí.[2]

Bí a ṣe ń tẹ ẹ̀bà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A ó gbé omi ka iná, tí ó bá ti gbóná, a ó da gàrí wa sínú rẹ̀ a ó wá ròó pọ dára dára kí ó lè lẹ̀ lọ́wọ́. A lè fi oríṣiríṣi ọbẹ̀ bíi: ọbẹ̀ ilá, ọbẹ̀ ẹ̀fọ́, ọbẹ̀ àpọn, ọbẹ̀ ẹ̀gúsí, omi ọbé ati ewédú pẹ̀lú ẹja òun ẹran oríṣiríṣi. [3]


Àwọn ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Recipe: How To Prepare Eba The Right Way". Modern Ghana. 2018-01-24. Retrieved 2019-06-08. 
  2. "What is Eba | How to Prepare Garri". allnigerianfoods.com. 29 December 2016. Retrieved 2018-11-14. 
  3. "Eba - Traditional Side Dish From Nigeria". TasteAtlas. 2016-12-07. Retrieved 2022-01-12. 

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Nigeria-cuisine-stub