Ẹ̀yà ara

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Òde Ara (Outer Part): Irun (hair), orí (head), iwájú (forehead), ojú (eye/face), imú (nose), àgbọ̀n (chin), ẹnu (mouth), orùn (neck), èjìká (shoulder), àyà (chest), ọmú/ọyàn (breast), apá (arm), ikùn (belly), idodo (navel), ọmọ ìka/ika ọwọ́ (fingers), èékánná (finger nail), ìdí (buttock), itan (thigh), ẹsẹ̀ (leg), orúkún (knee), ojúgun (shin), ìka ẹsẹ̀ (toes), àtẹ́lẹsẹ̀ (sole of the foot), and gìgísẹ̀ (heel).

Inú Ara (Inner Part): eyín (teeth), ahọ́n (tongue), ọ̀fun (throat), ọkàn (heart), ẹ̀dọ̀ fóró (lung) ẹ̀dọ̀ki (liver), ẹjẹ̀ (blood) and eran ara (muscle).