Ọ̀rọ̀:Salawa Abeni

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Salawa Abeni
Queen of Waka
Orúkọ àbísọSalawa Abeni Alidu
Ọjọ́ìbíOṣù Kàrún 5, 1961 (1961-05-05) (ọmọ ọdún 62)
Epe, Lagos State
Ìbẹ̀rẹ̀Epe
Irú orinWaka music
Occupation(s)Musician
Years active(1975 –present)
LabelsLeader records, Kollington, Alagbada

Won bi Salawa Abeni Alidu ni ( May 5, 1961) O je gbajugbaja olorin ni ile Yoruba. Nigerian singer.[1] O je of Ijebu Yoruba from Ijebu Waterside, ni ipinle Ogun State, O bere ere orin waka re nigba to waka music se awo orin re kan jade to pe ni: Late General Murtala Ramat Mohammed, ni odun 1976, ni eyi to towo Leader Record jade. Awo orin re yii lo mu ki o di ilu mooka obinrin akoko to se rekooodu sita ninu awon olorin ile Yourba, ni eyi to ta to milioonu kan awo orin naa nile Nijiiria.

Abeni tun te siwaju lati maa te awon awo orin olokan-o-jokan jade saaju ki o to fopin si ibasepo oun ati oga ile ise to n gbe awon awo re jade iyen record label's owner, Lateef Adepoju ni odun 1986. leyin eyi ni o fe gbaju-gbaja olorin fuji Kollington Ayinla ti gbogbo eniyan mo si Kebe-n-Kwara ti o si dara po mo ile ise ti o n gbe awo Kollington jade,ti ti di odun 1994.

Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Adeyemi in 1992 fi Oye 'Obabinrin Oni Waka' da Abeni lola "Queen of Waka Music" .[citation needed] Waka is an Islamic-influenced, traditional Yoruba music style, popularized by Batile Alake; it is a much older genre than jùjú and fuji.

  • Late Murtala Muhammed (Leader, 1976)
  • Iba Omode Iba Agba (Leader, 1976)
  • Shooting Stars (Leader, 1977)
  • Ijamba Motor (Leader, 1978)
  • Okiki Kan To Sele/Yinka Esho Esor (Leader, 1979)
  • Orin Tuntun (Leader, 1979)
  • Irohin Mecca (Leader, 1980)
  • Ile Aiye (Leader, 1980)
  • Omi Yale (Leader, 1980)
  • Ija O Dara (Leader, 1981)
  • Ikilo (Leader, 1981)
  • Enie Tori Ele Ku (Leader, 1982)
  • Challenge Cup ’84 (Leader, 1983)
  • Adieu Alhaji Haruna Ishola (Leader, 1985)
  • Indian Waka (Kollington, 1986)
  • Ife Dara Pupo (Kollington, 1986)
  • Mo Tun De Bi Mo Se Nde (Kollington, 1986)
  • Awa Lagba (Kollington, 1987)
  • Abode America (Kollington, 1988)
  • Ileya Special (Kollington, 1988)
  • I Love You (Kollington, 1988)
  • We Are The Children (Kollington, 1989)
  • Maradonna (Kollington, 1989)
  • Candle (Kollington, 1990)
  • Experience (Alagbada, 1991)
  • Congratulations (Alagbada, 1991)
  • Cheer Up (Alagbada, 1992)
  • Waka Carnival (Alagbada, 1994)
  • Beware cassette (Sony, 1995)
  • Live In London ’96 cassette (Emperor Promotions, 1996)
  • Appreciation cassette (Sony, 1997)
  • with Barrister Evening Of Sound cassette (Zmirage Productions, 1997)
  • Good Morning In America (Alagbada, 1999)
  1. Denselow, Robin (2001-07-20). "Queen Salawa Abeni". The Guardian. https://www.theguardian.com/culture/2001/jul/20/artsfeatures10. Retrieved 23 January 2010. 
  2. "Abeni, Queen Salawa." Encyclopedia of Popular Music, 4th ed.. Oxford Music Online. Oxford University Press, accessed February 17, 2016,


Àdàkọ:Nigeria-singer-stub