Jump to content

Ọọ̀ni Ifẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ère ilẹ̀ Yoruba tó ń ṣe àpejúwe ọba c. 1300
Ife bronze casting of a King, dated around twelfth century
Drummers at Ooni's Palace
A picture of an imagined Oduduwa sculpture at the Ooni of Ife palace

Ọọ̀ni ti Ilè-Ifẹ̀ ni orúkọ ọba aládé Ilé-Ifẹ̀ àti olórí nípa tẹ̀mí fún gbogbo ìran Yorùbá. Ipò Ooni ti wà ṣáájú ìjọba Oduduwa, èyí tí àwọn onímọ̀ sọ pé ó ti wà láti bíi sẹ́ńtúrì keje sí kẹsàn-án.

Lẹ́yìn ìpapòdà Oduduwa àti ìpàdánù orí-oyè fún Ogun, àwọn ọmọ lẹ́yìn Oduuwa tàn kárí Ile-Ife. Àmọ́ ìtàn mìíràn fi yé wa pé Ogun ló mọ̀ ọ́n mọ̀ rán àwọn ọmọ Oduduwa láti ṣe ìtànkálẹ̀ ìran Yoruba.

Lẹ́yìn ìṣèjọba Oduduwa, Obatala tún gorí oyè ní ẹlẹ́ẹ̀kejì, wọ́n sì í pín ètò ìṣèjọba láàárín ìdílé Obatala àti Obalufon títí Oranmiyan fi da ètò náà rú fúngbà díẹ̀. Ìtàn fi yé wa pé Ooni Lajamisan jẹ́ ọmọ Oranmiyan. Àmọ́, ìṣẹ̀ṣe Ife fi hàn pé Lajamisan jẹ́ ìran Oranfe ní tòótọ́. Síbẹ̀síbẹ̀, Lajamisan ni ó pàpà mú ọ̀làjú wọ Ifẹ̀.

Ṣáájú sẹ́ńtúrì ogún, ètò ìṣèjọba ń lọ létòlétò. Àmọ́, pẹ̀lú ọ̀làjú àti ìkónilẹ́rú, ètò náà yí padà, ó sì pín sí ìdílé mẹ́rin,[1] t í ṣe Ooni Lafogido, Ooni Osinkola, Ooni Ogboru àti Ooni Giesi. Ọọ̀ni tó ń jẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ni Adéyẹyè Ẹnitàn Ògúnwúsì, Ojaja II (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù kẹwàá, ọdún 1974).

Oríṣiríṣi ònkọ̀wé pẹ̀lú àtòjọ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìwé àti iṣẹ́ ìwádìí lóríṣiríṣi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Ojo Bada 1954[2] quotes 15 names for the Oduduwa to Lajamisan period.[3][4] See column 5.
  2. Chief Fabunmi 1975 quotes 7 names for the same period.[3] See column 6. Chief Fabunmi is known for his Historical notes.[5]
  3. Chief Fasogbon 1976 quotes 12 names for this period.[3] See column 7.
  4. Chief Awosemo 1985 quotes 22 names from Oduduwa to Giesi.[3] See column 8.
  5. Eluyemi 1986 quotes 41 names from Oduduwa to nowadays.[3] See column 9.

Orísun fún àtòjọ àkọ́kọ́ A list

  1. Awoyinfa, Dele, 1992 [6][7] pages 30–35.
  2. Prince L. A. Adetunji 1999,[8] pages 70–77. The prince, from the Giesi family, was one of the contenders for the 2015 designation.[9] See column LA.

Orísun fún àtòjọ è̩kejì B list

  1. Ologundu 2008,[10][11] pages 58–59. Lists 48 names, that are the B list, except from Obalufon Alayemore (#5) and Aworokolokin (#12). Moreover, Osinkola (#18) is at #25 (strange place) Araba Adedayo Ologundu was a native of Ile-Ife, Nigeria. See column Og.
  2. Lawal 2000,[12] page 21 (nevertheless, this book is Google described as a 19 pages book !). See column LB.

Àwọn orísun oríayélujára

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Source 2015.[13]
  2. Leadership.ng 2015.,[14] 2015. No references are given. One typo: Ademiluyi Ajagun (1930-19800).[15]
  3. Ooni Ojaja II web site,[16] 2016 quotes 51 names. Same as list B, differs only by the diacritics. No references are given. This list was already in use before 2015.

Ìfọbajẹ kì í ṣe isẹ́ tó rọgbọ rárá, ó sì ní àwọn tíwọ́n fi sípò láti máa fọba jẹ.[17][18] Ìfilélẹ̀ látẹnu àwọn afọbajẹ ní ọdún 1980 lábẹ́ Section 4(2). Ní ọdún 1957, ìfilélẹ̀ tí wọ́n ṣe fún ètò ìfọbajẹ ni:

  1. The Oshinkola House, Iremo (present) [as of 1957]
  2. The Ogboru House, Ilare
  3. The Giesi House, More
  4. The Lafogido House, Okerewe
Ojajii LB Eluyemi (x86)
Ogun Ogun Ogun
Odidimode Rogbeesin Odidimode Rogbesin
Gboonijio Gbodo-Nijio Gbodo-Nijio
Okanlajosin Okunlajosin -
Adegbalu Adegbolu Adegbolu
Luwoo Luwo (Female) Luwo (Female)
Ojelokunbirin Oje Lokunsinrin Ojee Lokunsinrin
Larunnka Larinka Larinka
Adegunle Adewela Adegunle Abeweela Abewela
Degbinsokun Degbin Kumbusu Degbinna-okun
Orarigba Orayigba Ojaja Orayigbi

Orúkọ àwọn Ọọ̀ni tó ti

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

1. Ọlọfin Odùduwà

2. Ọbàlùfọ̀n Ògbóderin

3. Ọbàlùfọ̀n Aláyémọrè

4. Òdelé Ọ̀rànmíyàn

5. Ọbalùfọ̀n Aláyémọré

6. Awoorokolokin

7. Èfọ̀n Ayíóyè

8. Àjímú Ẹkùn

9. Aláyémọrè ofifari láti ilé Molódò

10. Ọ̀sẹgànderùkù

11. Oyè

12. Lájàmìsán

13. Láàrókà

14. Owodo

15. Arírèré Ọ̀kínwo

16. Otataa

17. Lápeléke

18. Atújàbíòjò

19. Lúwogbàgìdá

20. Lájódogun

21. Lafogun

22. Láfogído

23. Ọọ̀ni Ọ̀sínkọ́lá

24. Ọọ̀ni Ògboòrú

25. Ọọ̀ni Gíẹ̀sí

26. Ọọ̀ni Adéjinlé

27. Ọọ̀ni Àróganganlàgbo

28. Ọọ̀ni Aríbiwóso

29. Ọọ̀ni Sọ́júolá

30. Ọọ̀ni Adésúnmákin

31. Ọọ̀ni Ọlọ́jọ

32. Ọọ̀ni Ọ̀sin-ín-ladé

33. Ọọ̀ni Ajífadésiré

34. Ọọ̀ni Àjílà Oòrùn

35. Ọọ̀ni Òjìgìdìrí

36. Ọọ̀ni Kúmóyèró Ọ̀dunlẹ̀bíòjò

37. Ọọ̀ni Gbániárè

38. Ọọ̀ni Gbégbáajé

39. Ọọ̀ni Wúmọníjẹ̀

40. Ọọ̀ni Adégúnlẹ̀ Abewéelá

41. Ọọ̀ni Dérin Kùm̀búsù

42. Ọọ̀ni Ọ̀ráyẹ̀gbà ọ̀jájá, 1878-1850

43. Ọọ̀ni Dérin Ọlọ́gbéńlá (kò dé adé), 1880-1894

44. Ọọ̀ni Adélékan Olúbùse I, 1894-1910

45. Ọọ̀ni Kọ́lá (Osù méjì péré), June – July 1910

46. Ọọ̀ni Àjàgún Adémilúyì, 1910-1930

47. Ọọ̀ni Sir Adésọjí Adérẹ̀mí, 1930-1980

48. Ọọ̀ni Okùnadé Ṣíjúwadé Olúbùṣe II, 1980 títí di òní

N.B:- Ní ayé ìgbàanì, àwọn baba-ńlá àti ìyá-ńlá wa kò mọ̀ nípa déètì. Ìdí nìyí tí kò fi sí àkọsílè déètì tí àwọn Ọọ̀ni ìgbà náà jẹ. Àkọsílẹ̀ déètì bẹ̀rẹ̀ láti ayé Ọọ̀ni Ọ̀ráyẹ̀gbà ọ̀jájá.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àtòjọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
LB Og 86 85 76 75 54 LA date name Notes nickname [8] comments [8]
0 0 0 0 0 0 0 0 Oranfe (Oramfe) Often regarded as the earliest ruler of Ile-Ife, otherwise known as Ugbomekun Okanranjigbo The ancestor of: Osangangan Obamakin, also known as Obalufon Ogbogbodirin; Obalufon Alayemore; and Lajamisan
0 0 0 0 0 0 0 0 Obatala Succeeded Oranfe. He was an important ruler of Ile-Ife whose authority was challenged through an usurpation Olufe, Olofin Iwase, Oseremagbo During the conflict that followed the usurpation of his leadership, he was able to retain the support of the larger number of the 13 major hamlets of the Ugbomekun confederacy who were regarded as 'Elu Meje'. Nonetheless, he lost the support of the other hamlets to Oduduwa, the head of the usurpation group.
0 0 0 0 0 0 0 0 Odùduwà Regarded as Olofin He headed 6 groups out of the 13 major hamlets of the confederacy. Had a troubled and short reign. Was upstaged by Obatala.
1 1 1 1 1 1 1 1 1 Obatala Seized power at the fall of Oduduwa and re-emerged as the king of Ife. He began the unification process of the previously semi-autonomous hamlets. His strong alliance with Osangangan Obamakin led to the rotation of power between the groups headed by both of them respectively
2 2 2 Ogun Compeer of Oduduwa. A great warrior and hunter who attempted to seize power but was ousted by Ọbalùfọ̀n Ògbógbódirin a.k.a Osangangan Obamakin
4 4 2 2 2 2 2 2 Ọbalùfọ̀n Ògbógbódirin S Oranfe Osangangan Obamakin (Orunmakin) Son of Oranfe. He lived and reigned for an unusually long period of time.
5 5 3 3 3 3 3 3 Ọbalùfọ̀n Aláyémọrẹ S Obalufon I Regarded as the First Ooni and carried out the complete unification of Ile-Ife[19] Became the Ooni after his father's death while Oranmiyan was on sojourn or exile. Abdicated after a stiff confrontation with Oranmiyan who returned to Ile-Ife.
6 5 4 4 4 4 4 Ọ̀raǹmíyaǹ S Ogun Odede=title ? A son of Ogun through a Lakange whom Oduduwa would later seize. Said to have lived between 1200 and 1300 A.D. Eweka, the Oba of Benin and Ajaka, the Alaafin of Oyo were his sons.
4.5 4.5 Ọbalùfọ̀n Aláyémọrẹ Onigbomore Back to the throne after Oranmiyan's death. Reigned at the same time as Dada, Alaafin of Oyo.
7 6 4.7 Ayétise
5 5 5 5 Àwórókọ̀lọ̀kín
6 4 4 5.5 5.5 Lajuwa (usurper) Okoo olori-ko-yun-ajo (A king's wife, called olorì is forbidden to travel) Head messenger. Said to have usurped the throne at the death of Aworokolokin.
6 7 6 6 Ẹ̀fọ̀n Ayíóyè Ogbolaajuree (no matter how ripe the okra is, it cannot be older than itself).
5 5 6 6 7 7 Ajímúda Ẹkùn
8 8 Láamórò Ògìján From Molodo compound, Ilode.
9 9 Ọ̀sẹgànderùkù Oseganderuku (He who turns the forest into dust).
6 7 9.5 Otaran
8 10 10 Ọyẹ́ Okukuyewu Ilode
8 10 10.7 Lamoro
8 7 7 10 12 7 15 11 11 Lájẹ̀misìn Son of Aiyetise and descendant of Oranmiyan (How?) or Son of Oranfe according to traditions established in Oranfe house [20] Modern Ife history began with his reign which was unusually long.
7 9 11 12 12 Lárọ́ọ̀ká From Moore. Claimed to be a descendant of Ọ̀ranmiyan and Ancestor of Giẹsi. There is one common saying: Larooka built the town hall and Giẹsi constructed a support for it at the bottom.
13 13 Òwódò From Okerewe.
8 12 14 14 Arírere Ọ̀kínwẹ
9 15 15 Ọtaataa Ọtaataa-kiran From Owodo. Alade yokun-saayo-lorun.
9 10 13 16 16 Lápeléke Oro-wuye-oluku-eti
11 14 16.2 Oluwo
17 17 Otújàbíòjò (who scatters the market like rainfall)
9 18 18 Lúwo Gbàgìdá Ayare, Akọsulogbe From Owode compound, Okerewe. Descendant of Otaataa (#15). She was married to Chief Ọbalọran of Ilode and became the mother of Adekola Telu, the founder of Iwo town. Was the only woman Ooni. .
9 8 19 19 Lájódogun S Lajamisan From Igbodo, Okerewe. Descendant of Lajamisan.
20 20 Lafogun From Igbodo. Descendant of Lajodoogun.
10 9 8 11 21 21 Láfogído D_Lajodogun From Igbodo. Descendant of Lajodoogun. Prominent among his children were: (1) Otutu biosun ? (2) Okiti #26.6 (3) Olojo Agbele #30 (4) Adagba #36.4 (5) Wunmọnijẹ #41 (6) Lugbade #26.7 (7) Lumobi #24.2 (8) Yeyelueko, mother of Singbunsin Yanningan ?
11 10 21.01 Odidimọdẹ Rogbẹṣin D_Lajodogun
12 21.02 Àwórókọ̀lọ̀kín D_Lajodogun
13 11 21.03 Ẹkun D_Lajodogun
14 12 21.04 Ajímúdà D_Lajodogun
12 21.1 Luciro
15 13 10 13 21.2 Gboo ni jio D_Lajodogun
16 14 11 14 21.4 Okunlajosin D_Lajodogun
17 15 12 15 21.6 Adégbàlú D_Lajodogun
13 16 21.8 Odidi Egbesin
18 14 17 22 22 Ọ̀sińkọ́lá D_Lajodogun Descendant of Lajodoogun.
18 22.2 Lagbuja
19 22.3 Omoropo
15 22.4 Lagunja
19 16 19 21 23 23 Ògbórú D_Lajodogun Descendant of Lajodoogun. Ogboruu was deposed after reigning for 70 years. Six princes were appointed successively within a year and all died without completing the coronation. Finally, Ogboruu agreeded to bless Giesi, a son of his daughter Mọropo
20 17 20 22 24 24 Gíẹ̀sí D_Lajodogun Maternal grandson of Ogboruu
21 18 24.1 Luwo D Lafogido
22 19 24.2 Lúmobi D of Lafogido
25 22 16 24.3 Lagunja D_Lajodogun
26 23 17 24.4 Larunka D_Lajodogun
27 24 18 20 24.6 Ademilu D_Lajodogun
25 24.8 Ọ̀sińkọ́lá
25 25 Adéjinlé Descendant of Owodo #13 and ancestor of Abeweela #42
26 26 Àróganganlàgbo From Akui.
24 21 21 26.3 Ojee lokun binrin D_Lajodogun
28 26 26.5 Ọmọgbogbo D_Lajodogun
30 28 24 26.6 Adejinlẹ D Lafogido
34 32 25 27 27 Aríbiwọsọ D Lafogido Aribiwoso-lode-Akui From Akui.
28 28 Ṣojuolu Ọ̀gbọnsẹ̀gbọndẹ From Owodo compound.
23 20 22 29 29 Agbẹ̀dẹ̀gbẹdẹ D_Lajodogun Descendant of Giẹsi.
31 29 26 30 30 Ọlọ́jọ́ D Lafogido Agbele-wojuorun-yanmongi From Okerewe.
32 30 30.3 Okiti D Lafogido
33 31 30.6 Lúgbadé D Lafogido
32 32 Ajífadéseré
33 33 Otuko
34 34 Odidimọdẹ Rogbẹṣin Ancestor of Mọlodo, Awura and Lami (?,?,?)
29 27 23 35 35 Ajílà Oòrùn D_Lajodogun From Moore. Descendant of Agbedegbede #29
35 33 27 31 35.5 Ọ̀sinínladé Òtutùbiọ̀ṣun D Lafogido Descendant of Lafogido.
36 36 Abigboọla
36 34 36.4 Àdàgbá D Lafogido
37 35 28 37 37 Òjìgìdìrí D_Lajodogun Lambuwa. From Akui ward, Ife.
38 36 29 38 1770−1800 Akínmóyèró D Lafogido Iriko dunle biojo (the mist cannot wet the ground like rain).
39 37 30 39 1800−1823 Gbániárè D_Lajodogun Gbadioro at x86 From Ilare ward, Ife.
40 38 31 40 1823−1835 Gbégbáajé D_Lajodogun
41 39 32 41 1835−1839 Wúnmọníjẹ̀ D Lafogido Wunmo-nije-soogun A descendant of Lafogido.
42 40 33 42 1839−1849 Adégúnlẹ̀ Abewéilá D Lafogido Abewe-ila gberengedẹ (spread out like the leaf of the okra plant). He is said to have died at about 35 years of age.
43 41 34 43 1849−1878 Degbin Kùmbúsù D Lafogido The first fall of Ife occurred during his reign in 1849.
44 42 35 44 1878−1880 Ọ̀ráyẹ̀gbà Ọjaja D_Lajodogun Ayikiti-ninu-aran (rolls around in velvet fabric). Imposed by the Ibadan.
45 43 36 45 1880−1894 Dérìn Ọlọ́gbénlá D Giesi Ooni-elect, who never came to be crowned at Ife before he died at Okeigbo. During his reign, the second fall of Ife occurred in 1882.
46 44 37 46 1894−1910 Adélékàn Olúbòse I D Ogboru Eriogun, Akitikori, Ebitikimopiri First Ooni to reign in Ile Ife after the end of Ekitiparapo war. The evacuation of Modakeke occurred during his reign.
47 45 38 47 1910−1910 Adékọ́lá D_Lajodogun Lawarikan, Agbejanla-bofa. From Akui. An Ooni-elect for only two months, June–July 1910.
48 46 39 48 1910−1930 Adémilúyì Àjàgún D Lafogido He was a descendant of Otutubiosun #31. During his reign the Modákẹ́kẹ́ people returned to Ifẹ̀ in 1921.
49 47 40 49 1930−1980 Adesoji Aderemi D Osinkola Ainla, Ọmọ Adekunbi Ipetu From Akui. death=3/7/1980. Was a descendant of Ojigidiri Lambuwa (#37)
50 48 41 50 1980−2015 Olubuse II D Ogboru Grandson of Adelekan Olubuse. death=28/7/2015. Communal clashes between Modakeke and Ife people was reignited during his reign.

Sijuade Olubuse II banned the sale of the Adetunji's book in ife town because it included a story pertaining to his grandfather Adélẹkàn Olúbùse, which he did not want publicized

51 51 2015− Adeyeye Enitan Ogunwusi Ojaja II D Giesi

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "The Place Of Oranmiyan In The History Of Ile – Ife". Vanguard (Nigeria). 2016-02-22. http://www.vanguardngr.com/2016/02/the-place-of-oranmiyan-in-the-history-of-ile-ife. Retrieved 2016-04-20. 
  2. Ojo, Bada of Shaki (1954). Iwe Itan Yoruba. Apa Kinni, Ibadan, 228 pages.  Cited from Ojuade & Obayemi, not read directly.
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 3.4 J Sina Ojuade (1992). "The issue of Oduduwa in Yoruba genesis: the myths and realities". Transafrican Journal of History 21: 139–158. JSTOR 24520425.  (p.154)
  4. Ade Obayemi (June 1979). "Ancient Ile-Ife: Another Cultural Historical Reinterpretation". Journal of the Historical Society of Nigeria 9 (4): 151–185. JSTOR 41857206.  (p.158)
  5. M. A. Fabunmi (1985). An Anthology of Historical Notes on Ife City. J. West Publications. pp. 282. ISBN 9789781630170. 
  6. Awoyinfa, Dele (1992). Ooni of Ife in Yoruba history. Lichfield Nigeria. p. 96. ISBN 9789783049871. https://books.google.com/books?id=x30uAQAAIAAJ. 
  7. "Awoyinfa, Dele". Worldcat. Retrieved 2016-04-23. 
  8. 8.0 8.1 8.2 Prince L. A. Adetunji (1999). The Glory of Yoruba Nation. Lichfield Nigeria. pp. 128. ISBN 9789783049871. 
  9. "The Ooni has spiritual and physical powers". Vanguard (Nigeria). 2015-08-30. Retrieved 2016-04-21. 
  10. Ologundudu, Dayo (2008). The cradle of Yoruba culture. Center for Spoken Words. p. 206. ISBN 9780615220635. https://books.google.com/books?id=Vn8uAQAAIAAJ. 
  11. Searchworks. Archived from the original on 2016-05-12. https://web.archive.org/web/20160512203516/https://searchworks.stanford.edu/catalog/citation?id=10702157. Retrieved 2022-10-22. 
  12. Lawal, Ladun Kofoworola Owolade (2000). Ile-Ifẹ : the cradle of the Yoruba : with Oduduwa as their progenitor. Ikoyi, Lagos : Ayojide Enterprises. p. 19. https://books.google.com/books?id=7R8_AQAAIAAJ. 
  13. http://ilfng.org/The-source.html, trustees= Chief Kemade Elugbaju, Hon. Rotimi Makinde, Dr. Akin Awofolaju, Dr. Ramon Adedoyin, Niyi Murele, Sen. Babajide Omoworare, Prince Adedamola Aderemi, Kehinde Awoyele, Prince Adeleke Ijiyode
  14. "Ooni Of Ife: Ademiluyi Family Set To Produce Successor". Leadership Newspaper. 2015-07-30. Retrieved July 30, 2015. 
  15. "Ooni Ogun & The Obalades crown chiefs of Yoruba Land". Adebola Opaleye. Retrieved 5 August 2020. 
  16. "Past Ooni of Ife". Archived from the original on 2016-05-04. Retrieved 2016-04-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  17. Olufemi Vaughan (2006). Nigerian Chiefs: Traditional Power in Modern Politics, 1890s-1990s. Rochester studies in African history and the diaspora. University Rochester Press. p. 168. ISBN 9781580462495. https://books.google.com/books?id=LtAkDl3OrQgC. 
  18. Dr. Abiola Sanni. "Erring on the law to fill Ooni stool". Bar Alpha (Nigeria). Archived from the original on 2016-06-02. Retrieved 2016-04-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  19. Suzanne, Blier (2014). "Kings, Crowns, and Rights of Succession: Obalufon Arts at Ife and other Yoruba Centers". The Art Bulletin 67 (3). 
  20. Akinjogbin, I. A. (1992). The Cradle of a Race: Ife from the Beginning to 1980. Port Harcourt: Sunray Publications Limited.