Abíọ́lá Ọdẹ́jídé
Abíọ́lá Ọdẹ́jídé | |
---|---|
Ọ̀jọ̀gbọ́n-ágbà nínú ìmọ̀ iṣẹ́-ọ̀nà èdè àti lítíréṣọ̀ láti Yunifásítì Ìbàdàn, (University of Ibadan) | |
In office 2011 – present | |
Ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ iṣẹ́-ọ̀nà èdè àti lítíréṣọ̀ láti Yunifásítì Ìbàdàn, (University of Ibadan) | |
In office 1991–2011 | |
Igbákejì ọ̀gá Yunifásítì lábala ètò ẹ̀kọ́ ní University of Ibadan | |
In office November 8, 2004 – November 7, 2006 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kẹrin 1946 |
Residence | Ibadan, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ |
Alma mater | University of Ibadan (Bachelor of Arts in English) University of Leeds ( Master of Arts in Linguistics and English Language Teaching) University of Ibadan (Doctor of Philosophy in English: Children Literature) |
Abíọ́lá Ọdẹ́jídé jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n-ágbà nínú ìmọ̀ iṣẹ́-ọ̀nà èdè àti lítíréṣọ̀ láti Yunifásítì Ìbàdàn, (University of Ibadan). Ó ti kọ́kọ́ jẹ Igbákejì ọ̀gá Yunifásítì lábala ètò ẹ̀kọ́ ní University of Ibadan, òun sìn ni obìnrin àkọ́kọ́ tó kọ́kọ́ dé irú ipò bẹ́ẹ̀ lọ́mọ ọdún méjìdínlọ́gọ́ta.[1]
Ìgbà èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Abíọ́lá Ọdẹ́jídé kàwé gboyè dìgírì àkọ́kọ́ pẹ̀lú èsì ìdánwò tó dára nínú ìmọ̀ èdè òyìnbó ní University of Ibadan lọ́dún 1968. Lẹ́yìn náà, ó lọ sí University of Leeds lókè òkun láti kàwé gboyè dìgírì kejì nínú ìmọ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ ti Lìnùngúísítì àti èdè òyìnbó pẹ̀lú èsì tó dára jù lọ lọ́dún. Ó gboyè ọ̀mọ̀wé lọ́dún 1986,ó sìn di ọ̀jọ̀gbọ́n yányán lọ́dún 1991 ní University of Ibadan.[2]
Àwọn ipò aṣojú tó dìmú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdẹ́jídé ni obìnrin àkọ̀kọ̀ tí ó k9kọ́ jẹ Igbákejì ọ̀gá Yunifásítì ní University of Ibadan.[3] A¡ṣáájú àkókò náà, ó ti kọ́kọ́ di oríṣiríṣi ipò mú, lára àwọn ipò tó jẹ ni; Olùdarí ìkẹ́kọ̀ọ́ òkèèrè. Ó sinmi lẹ́nu iṣẹ́ ní Ìbàdàn lóṣù kọkànlá ọdún 2011. [4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Published. "People asked who’d take care of my home if I became DVC –Prof Odejide, UI ex-deputy vice-chancellor". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-28.
- ↑ admin (2017-11-21). "Abiola Odejide CV" (PDF). University of Ibadan. Archived from the original (PDF) on 2019-07-01. Retrieved 2017-11-21.
- ↑ admin (January 25, 2015). "UI gets new Deputy Vice-Chancellor". Vanguard (Nigeria). Retrieved 2017-11-21.
- ↑ "I FELT A SENSE OF HISTORY BECOMING FIRST FEMALE DVC". Nigeria Voice. November 21, 2017. Retrieved 2017-11-21.