Abula (ọbẹ̀)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Amala pelu obe Abula

Àbùlà jẹ ọ̀kan lára ọbẹ̀ àwọn YorùbáÌwọ̀ Oòrùn Nàìjíríà. [1] Wọ́n ma ń sábà jẹ ọbẹ̀ náà pẹ̀lú Amala, ṣugbọn ó sé fi jẹ àwọn ounjẹ òkèlè miiran. Àdàlù oríṣi ọbẹ̀ ni Abula túmọ̀ sí, ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n ó ma ún sábà túmọ̀ sí àdàlù gbegiri (ọbẹ̀ ẹ̀wà), Ewedu àti ọbẹ̀ ata. [2]

Wọ́n má ń ká àbùlà si ọbẹ̀ aládùn kò sì ún ṣe ọbẹ̀ tí wón dédé sẹ̀. Ṣíṣe rè ma ún gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ akitiyan àti àkókò. Àwọn Yoruba ní ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà ní o ma ún sábà ṣe ọbẹ̀ yìí, pàá pàá jùlọ, àwọn èèyàn Ọ̀yọ́ àti Ogbómọ̀ṣọ́.[3]

Wo eyi naa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Amala and Abula". Nigerian Tribune. 2018-02-10. Archived from the original on 2019-04-27. 
  2. "Best Nigerian Recipes for this weekend - Abula". The Nation. 2017-10-20. 
  3. "Ogbomoso Ajilete group celebrates Amala, Gbegiri Day". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-29. Retrieved 2022-02-26.