Ògbómọ̀sọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ògbómọ̀sọ́ jẹ́ ìlú ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yo ní apá ìwò-oòrùn oriĺè-èdè Nàìjíríaì. A dá ìlú Ògbómọ̀sọ́ sílẹ̀ ní 17th Century.[1] Àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn tí ó wà níbè gẹ́gẹ́ ètò ìkànìyàn ọdún 2006 sọ jẹ́ 645,000.[2] Yorùbá pó́ńbélé ni ọ̀pọ̀ àwọn òlùgbé Ògbómọ̀sọ́. Iṣẹ́ àgbẹ́ iṣu, gbágùúdá, àgbàdo àti ewé sìgá jẹ́ lára àwọn iṣẹ́ tó gbajúmọ̀ jùlo ni Ògbómọ̀sọ́.[3]

References[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Empty citation (help) 
  2. Empty citation (help) 
  3. "Ogbomosho". Columbia Encyclopedia (5th ed.). Columbia University Press. 1993. pp. 1997. http://columbia.thefreedictionary.com/Ogbomosho. Retrieved 2007-04-01.