Ado (Lagos Oba)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ado
Reign 1716–1755
Coronation 1716
Predecessor Ashipa
Successor Gabaro
Issue
Gabaro, Akinsemoyin, Erelu Kuti
Father Ashipa
Born Benin

Oba Ado (orukọ Bini atilẹba ni Edo) [1] [2] ti o jọba lati 1630-1669 ni Oba keji ti Eko . Ó jẹ́ ọmo ilu Áṣípà, ẹni tí Ọba Bénì yàn gẹ́gẹ́ bí olórí àkọ́kọ́ ní Eko . [2] [3] Omo Ado, Gabaro ni Oba keta ti ilu Eko.

Oba keji ti Eko[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ado gba owo-ori lọdọọdun lọwọ awọn ọmọ abẹ rẹ ti wọn si fi ma ranṣẹ si Ọba ti Benin gẹgẹ bi owo-ori.

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Saburi Oladeni Biobaku (1973). Sources of Yoruba history: Oxford studies in African affairs. Clarendon Press, 1973. p. 39. ISBN 978-0-19-821669-8. https://books.google.com/books?id=gGl1AAAAMAAJ&q=guobaro. Retrieved 30 July 2017. 
  2. 2.0 2.1 Deji Ogunremi (1998). Culture and society in Yorubaland. Rex Charles Publication in association with Connel Publications, 1998. p. 80. ISBN 9789782137739. https://books.google.com/books?id=Dm8uAQAAIAAJ&q=guobaro. Retrieved 30 July 2017. 
  3. Remi Olajumoke (1990). The Spring of a Monarch: The Epic Struggle of King Adeyinka Oyekan II of Lagos. Lawebod Nigeria, 1990. p. 39. ISBN 9789783088504. https://books.google.com/books?id=mggzAAAAIAAJ&q=ashipa+1600. Retrieved 30 July 2017.