Akinsemoyin
Ìrísí
Akinsemoyin | |
---|---|
Reign | c1704 - 1749 |
Predecessor | Gabaro |
Successor | Eletu Kekere |
Issue | |
Sadeko, Amore/Olukokun, Abisako, Jolasun, Gbosebi and Aina Egbe[1] | |
Father | Ado |
Born | Lagos |
Died | Lagos |
Burial | Benin |
Oba Akinsemoyin jẹ́ Oba Èkó láti ọdún 1704 sí 1749. Bàbá rẹ̀ ni Oba Ado, àwọn ẹbí rẹ̀ sì ni Erelu Kuti àti Oba Gabaro, ẹni tí ó jọba ṣáájú Akinsemoyin.[2]
Gégé bí Justice J. O. Kassim ṣe fi léde ní ọjọ́ kàndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1978, ọmọ ọkùnrin mẹ́fà ni Akinsemoyin ní, orúkọ wọn ni, Sadeko, Amore/Olukokun, Abisako, Jolasun, Gbosebi àti Aina Egbe.[1]
Díè tí ó gbajúmọ̀ nínú àwọn ọmọ ọmọbìnrin Akinsemoyin ni: Onisiwo, Oniru, Oluwa, àti Akogun.[3][4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Osuntokun, Akinjide (1987). History of the Peoples of Lagos State. Lantern Books, 1987. pp. 44. ISBN 9789782281487.
- ↑ Mann, Kristin (2007). Slavery and the Birth of an African City: Lagos, 1760-1900. Indiana University Press, 2007. p. 45. ISBN 9780253348845. https://archive.org/details/slaverybirthafri00mann.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedCole
- ↑ "Chief Yesufu Abiodun Oniru". Facebook.
- ↑ Rufus T. Akinyele (2009). African Cities: Competing Claims on Urban Spaces. BRILL, 2009. pp. 115–117. ISBN 9789004162648. https://books.google.com/books?id=A_IsNliDF6kC&dq=oniru+oluwa+onisiwo&pg=PA115.