Eletu Kekere

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Oba Eletu Kekere, je omo oba Gaboro, ti o jo ba ni shoki gege bi oba ti ilu Eko, leyin ti oba Akinsemoyin de ku ni odun 1775. [1] A ko mọ pupọ nipa ijọba Eletu Kekere yatọ si pe ko ni ọmọ. [2]

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Mann, Kristin. Slavery and the Birth of an African City: Lagos, 1760-1900. Indiana University Press, 2007. p. 45. ISBN 9780253348845. 
  2. Shodipe, Uthman. From Johnson to Marwa: 30 years of governance in Lagos State. Malhouse Press, 1997. p. 245. ISBN 9789780230692.