Jump to content

Ologun Kutere

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ologun Kutere
Oba Èkó
c. 1780 - 1806
Eletu Kekere
Adele Ajosun
Issue
Eshinlokun, Adele Ajosun, Akiolu, Olukoya, Olusi and Akitoye.
[[Royal house|]] Ado, Ologun Kutere
Father Alaagba
Mother Erelu Kuti
Born Lagos
Died c. 1803
Lagos
Religion Ifá

Ologun Kutere jẹ gẹ́gẹ́ bi Oba Èkó láti 1780s títí di ọdún 1803.[1] Òun ló jẹ́ lẹ́yìn Oba Eletu Kekere, ẹni tí ó wà lórí oyè láti ọdún sí 1775 and 1780.

Ologun Kutere jẹ́ ọmọ Erelu Kuti, ẹni tí ó jé ọmọ Oba Ado, àti Alaagba ('Alagbigba'), ẹni tí ó jẹ́ ọmọ Ìjẹ̀sà àti olùbádámọ̀ràn Oba Akinsemoyin.[2]

Bàbá Kutere jẹ́ Babaláwo ní Ìpínlẹ̀ Èkó nígbà àwọn ọdún 1700s.[3] Nígbà tí Kutere wà lórí oyè, ìbárà láàrin Èkó àti and Ijebu wọ́pọ̀ si, àwọn Ìjẹ̀bú gbé oúnjẹ wá láti gba iyọ̀, tobacco, spirits, àti àwọn ìkan míràn tí àwọn Èkó gbà lọ́wọ́ àwọn ara ẹrú tí orílẹ̀ èdè Portugal. Ologun Kutere lówó, ó sì jẹ́ ẹni tí ọ̀pọ̀ bẹ̀rù.[4]

Kutere ní ọmọ tópọ̀, àwọn bi;Eshinlokun, Adele Ajosun, Akitoye, Akiolu, Olukoya, àti Olusi.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Mann, Kristin (2007). Slavery and the Birth of an African City: Lagos, 1760-1900. Indiana University Press, 2007. p. 45. ISBN 9780253348845. https://archive.org/details/slaverybirthafri00mann. 
  2. Hassan Adisa Babatunde Fasinro. Political and cultural perspectives of Lagos. s.n., 2004. p. 46. 
  3. Olupona 2008, p. 177.
  4. John Adams (1823). Remarks on the Country Extending from Cape Palmas to the River Congo. G. & W.B. Whittaker, 1823. p. 100. https://archive.org/details/remarksoncountr01adamgoog. 
  5. 'Diméjì Ajíkòbi. What Does an African 'new Woman' Want?. Ark Publications, 1999. p. 46. ISBN 9789783488694.