Adele Ajosun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adele
Oba Èkó
c 1811 - 1821
1835 - 1837
Ologun Kutere 1st term predecessor
Idewu Ojulari 2nd term predecessor
Osinlokun 1st term successor
Oluwole 2nd term successor
Issue
Oluwole
[[Royal house|]] Ado, Ologun Kutere
Father Ologun Kutere
Born Lagos
Died 1837
Lagos
Burial Lagos
Religion Ifá

Oba Adele tàbí Adele Ajosun (ó fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 1837) jọba ní Èkó fún ṣáà méjì; àkọ́kọ́ , láti ọdún c1811 sí 1821, àti ẹlẹ́kejì láti ọdún 1835 sí 1837. Bàbá rẹ̀ ni Oba Ologun Kutere, àwọn ẹbí rẹ̀ sì ni Oba Osinlokun àti Ọba Akitoye, ìran Ologun Kutere ti gun orí oyè ọba Èkó fún ọ̀pọ̀ ìgbà láti ìgbà náà.[1]

Dídé ori oyè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adele gun orí ìtẹ́ ọba Èkó lẹ́yìn ọdún márùn-ún tí bàbá rẹ̀, Ologun Kutere, fi ayé sílẹ̀. Àwọn ìtàn àti àkọọ́lẹ̀ kòkan fihàn pé ète Ologun Kutere ni pé kí Adele di Oba Èkó nítorí iṣẹ́ ribiribi tí ó ti ṣe fún Ologun Kutere. Onítàn John. B. Losi kọ́ pé Adele tọ́ju àwọn ohun ìní Ologun Kutere.

Nígbà ìjọba Adele, ẹ̀sìn Mùsùlùmí gba ilẹ̀ ní Èkó.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Mann, Kristin. Slavery and the Birth of an African City: Lagos, 1760-1900. Indiana University Press, 2007. p. 45. ISBN 9780253348845.