Afárá Third Mainland
Appearance
Third Mainland Bridge | |
---|---|
Carries | Vehicular Traffic |
Crosses | Lagos Lagoon |
Locale | Lagos, Nigeria |
Toll | No |
Afárá Third Mainland tabi Third Mainland Bridge ni o gunjulo ninu awon afara meta to sejapo Erekusu Eko, Lagos, Nigeria mo oluile, awon meji to ku ni afara Eko ati Carter. Ohun ni afara to gunjulo ni Africa. Afara Third Mainland bere lati Oworonshoki to jamo ojuona Apapa-Oshodi ati ojuona Lagos-Ibadan, o si dopin ni iyana Adeniji Adele ni Lagos Island. Ile-ise Julius Berger Nigeria PLC lo ko ni 1990 labe ijoba ologun Aare Ibrahim Babangida. Igun re je 11.8km.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |