Jump to content

Ajo National Agency for the Prohibition of Trafficking in Persons

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use Nigerian English Àdàkọ:Third-party

National Agency for the Prohibition of Trafficking in Persons
overview
Formed 14 July 2003 (14 July 2003)
Jurisdiction Federal Government of Nigeria
Headquarters Abuja, FCT, Nigeria
Motto Empowered to protect you
executives Imaan Sulaiman – Ibrahim, Director General;
Hassan Hamis Tahir, Director Legal and Prosecution;
Arinze Orakwue, Director Public Enlightenment;
Godwin Morka, Director Research and Programme Development;
Olubiyi Olusayo, Director Training and Manpower Development;
Josiah Emerole, Director, Investigation and Monitoring;
Effeh Ekrika, Director Administration;
Ebele Ulasi, Director Counseling and Rehabilitation;
Sambo Abubakar, Director Finance and Accounts.
Parent Federal Ministry of Humanitarian Affairs, Disaster Management and Social Development
Website
naptip.gov.ng/

National Agency for the Prohibition of Trafficking in Persons (NAPTIP) jẹ́ àjọ agbófinró ìjọba-àpapọ̀ orílè-èdè Nàìjíríà tí wọ́n dá sílẹ̀ lọ́dún 2003 láti gbógun ti kíkó ènìyàn lọ sí òkè-òkun lọ́nà àìtó àti àwọn ọ̀ràn mìíràn tó jẹ́ mọ àtakò ẹ̀tọ́ ọmọ-ènìyàn.

NAPTIP jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àjọ tí ó wà lábé Federal Ministry of Humanitarian Affairs, Disaster Management and Social Development.

Wọ́n dá àjọ NAPTIP sílẹ̀ lábẹ́ ìwé àbádòfin ìjọba àpapọ̀ lọ́jọ́ kẹrìnlá oṣù keje ọdún 2003[1] pẹ̀lú òfin lábẹ́ òfin tó tako kíkó ọmọnìyàn ròkè-òkun lọ́nà àìtọ́, (Trafficking in Persons(Prohibition) Enforcement and Administration Act) ti ọdún (2003)[2] nípa ìrànlọ́wọ́ ètò àtakò kíkó obìnrin àti àwọn ọmọdé re òkè òkun lọ́nà àìtọ́ tí àjọ Women Trafficking and Child Labour Eradication Foundation (WOTCLEF).

Wọ́n dá àjọ NAPTIP sílẹ̀ pẹ̀lú èròǹgbà láti ṣe ìgbófinrò àwọn òfin tí tó tako kíkó ènìyàn lọ sókè òkun lọ́nà àìtó lábẹ́ òfin Trafficking in Persons(Prohibition) Enforcement and Administration Act (TIPPEA) ní Nigeria [3]

Láti lè ṣe iṣẹ́ rẹ̀ dáradára tako kíkó ènìyàn rèlú òyìnbó lọ́nà àìtọ́, wọ́n pín àjọ yìí sí ẹlẹ́kajẹ̀ka àti ìpẹ̀ka wọ̀nyí:[4]

  • Ìwádìí àti Ìmójútó.
  • Òfin àti Ìpẹ̀jọ́.
  • Ìgbaninímọ̀ràn àti Aṣàtúnṣe.
  • Ìdáni kẹ́kọ̀ọ́ láwùjọ.
  • Ìwádìí àti Ìṣètò
  • Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àti Ìrónilágbára.
  • Ádárì Ilé-iṣẹ́
  • Ìsúná-owó àti Ìṣirò-owó.

Àwọn apẹ̀ka

  • Ríra nǹkan
  • Ìròyìn àti ìbáṣepọ̀ àwọn ènìyàn.
  • Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ àti ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn orílẹ̀ èdè mìíràn
  • Àyẹ̀wò
  • Àtúnṣe.
  • Ìdáhùn sí ìṣẹ̀lẹ̀ ní yàjóyàjó, (Rapid Response Squad) [5] (RRS)

Àwọn ẹ̀ka àjọ yìí ní Ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní báyìí, àjọ yìí ní ẹ̀ka ní Èkó, Benin, Enugu, Uyo, Sokoto, Maiduguri, Oshogbo, àti Makurdi.[6]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Ibenegbu, George (28 November 2017). "Top 10 functions of NAPTIP". Naija.ng - Nigeria news. (Naij.com). https://www.naija.ng/1137337-meaning-functions-naptip-nigeria.html#1137337. Retrieved 12 May 2018. 
  2. "About NAPTIP – NAPTIP". www.naptip.gov.ng. NAPTIP. Archived from the original on 23 April 2022. Retrieved 12 May 2018. 
  3. "Functions Of NAPTIP | Passnownow.com". passnownow.com. Passnownow. Retrieved 12 May 2018. 
  4. "Human Trafficking Day: NAPTIP rescues 14,000 victims in 16 years" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-31. Retrieved 2022-03-29. 
  5. "NAPTIP inaugurates new Squad to fight human trafficking - News Agency of Nigeria (NAN)". News Agency of Nigeria (NAN) (News Agency of Nigeria). 22 August 2017. http://www.nan.ng/news/naptip-inaugurates-new-squad-fight-human-trafficking/. Retrieved 13 May 2018. 
  6. "NGP WRF: Organizations". wrf.nigeriagovernance.org (Nigerian Governance). http://wrf.nigeriagovernance.org/organizations/view/950. Retrieved 13 May 2018.